Eyi ni awọn ohun ti mo ba Aarẹ Buhari sọ lasiko abẹwo mi si i l’Abuja-Makinde

Gomina ipinlẹ Ọyọ ati Ondo, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde ati Akeredolu, ṣabẹwo si Aarẹ Buhari ni Aso…

Wọn fẹẹ lu Taju pa n’Ibadan, iyawo ẹ lo purọ ole mọ ọn 

Ọlawale Ajao, Ibadan Ori lo ko baale ile kan, Tajudeen Olufade, yọ nigboro Ibadan laipẹ yii…

Koronafairọọsi pa ọga agba kan nileewe Yaba Tech

Jide Alabi Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii nileewe gíga Yaba Tech, l’Ekoo, paṣẹ pe ki gbogbo awọn…

Ko pẹ ti Rauf gba igbega lẹnu iṣẹ ọlọpaa ni wọn ni awọn ọtẹlẹmuyẹ pa a l’Osogbo

Florence Babaṣọla Ko sẹni to le de agbegbe ọja Olobu, nijọba ibilẹ Irẹpọdun, nipinlẹ Ọṣun, nibi…

Lebira yii yoo ṣẹwọn o, owo ọga rẹ lo ji n’Ileefẹ

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Adajọ ile-ẹjọ Majisreeti kan niluu Ileefẹ ti sọ pe ki wọn lọọ fi…

Ọdun mẹtadinlọgọrin ni Abioye yoo lo lẹwọn, jibiti owo nla lo lu

Faith Adebọla, Eko Ile-ẹjọ to n gbọ awọn ẹsun akanṣe to wa n’Ikẹja, nipinlẹ Eko, ti…

Lọjọ kan ṣoṣo, arun Korona pa eeyan marun-un nipinlẹ Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Wọn ti kede bayii pe laarin ọjọ kan ṣoṣo, eeyan marun-un ni wọn…

Eyi ni awọn ti Buhari ṣẹṣẹ yan gẹgẹ bii olori awon ọmọ ogun gbogbo nilẹ wa

Lẹyin gbogbo ariwo ti awọn ọmọ Naijiria ti n pa latọjọ yii wa, lana an ọjọ…

Ọpẹ o, Buhari ti le awọn ologun rẹ lọ, o fi awọn tuntun rọpo wọn

Aarẹ Muhammadu Buhari ti le awọn ọga ileeṣẹ ologun ilẹ wa danu, bẹẹ lo si fi…

Niṣe lawọn ti wọn jo ile Sunday Igboho n yinbọn soke kẹu kẹu laarin oru

Ileeeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ ti sọ pe ki i ṣe pe ile Sunday Adeyẹmọ ti gbogbo…

Ọwọ Amotẹkun ti tẹ awọn Fulani ajinigbe ti wọn n kogun lọ s’Ibarapa o

Ọwọ awọn Amotẹkun ti tẹ awọn Fulani ajinigbe ti wọn n kogun lọ si Ibarapa o…