Jamiu atawọn ọrẹ ẹ ṣa Akinọla pa sile ounjẹ l’Alapẹrẹ

Faith Adebọla, Eko Iku gbigbona, iku oro, lawọn afurasi ọmọ ẹgbẹ okunkun kan fi pa ọdọkunrin…

Ere to pọ n bẹ fun agbofinro to ba ṣiṣẹ rẹ bo ṣe yẹ – Ọga ọlọpaa patapata

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ọga ọlọpaa patapata lorilẹ-ede yii, Mohammed Adamu, ṣabẹwo solu ileeṣẹ ọlọpaa to wa…

O ma ṣe o, awọn agbebọn yinbọn pa ọba alaye l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ṣe ni ibanujẹ dori agba awọn eeyan ijọba ibilẹ Ifọn, nijọba ibilẹ Ọsẹ,…

Nitori awọn aṣofin ti wọn yọ nipo l’Ondo, ile-ẹjọ fiwe pe olori ile-igbimọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Olori ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Ondo, Ọnarebu David Bamidele Ọlẹyẹlogun, ti gba iwe waa…

Awọn ọlọpaa lẹtọọ lati gbe ibọn, ki wọn le fi daabo bo araalu lọwọ ewu-Adamu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọga agba patapata fun ileesẹ ọlọpaa orileede yii, Adamu Muhammed ti gba awọn…

Taofik to lu Ọlayẹni ni jibiti miliọnu mẹẹẹdọgbọn naira l’Akurẹ ti dero kootu

Ileeṣẹ ọlọpaa nipinlẹ Ondo ti wọ ọkunrin kan, Ọlayiwọla Taofik, lọ sile-ẹjọ Majisireeti kan niluu Akurẹ lori ẹsun…

Arẹgbẹṣọla, fi Oyetọla lọrun silẹ, jẹ ko raaye ṣejọba l’Ọṣun – Oyinlọla

Idowu Akinrẹmi, Ikire Ọmọọba Ọlagunsoye Oyinlọla ti i ṣe gomina ipinlẹ Ọṣun tẹlẹ, ti rọ Ọgbẹni…

Awọn aṣofin mẹsan-an lawọn ko lọwọ ninu bi wọn ṣe yọ igbakeji olori wọn l’Ondo

Dada Ajikanje Awọn ọmọ ile-igbimọ aṣofin mẹsan-an ni wọn ti ta ko bi wọn ṣe yọ…

Iku Nikẹ Ọpẹifa di ariyanjiyan, wọn ni ọkọ ẹ lo pa a, akọbi ẹ ni funra iya oun lo gbe majele jẹ

Jide Alabi Iku abilekọ kan, Nikẹ Ọpẹifa, ti di ariyanjiyan bayii lori bi awọn eeyan obinrin…

Pasitọ wa n ba iyawo mi lo pọ, mi o fẹ ẹ mọ – Johnson

Idowu Akinrẹmi, Ikire Baale ile kan, Olumuyiwa Johnson, wa si kootu ibilẹ to wa ni Mapo,…

Aje o! Reluwee pa maaluu mẹtadinlaaadọta l’Oṣogbo

Florence Babasola, Oṣogbo Ọkọ reluwee kan to yawọ la gbọ pe o pa maalu mẹtadinlaaadọta ti…