Ọmọ ọjọ kan ti wọn gbe jade ninu sọkawee l’Adiyan ṣi n gbatọju lọsibitu

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Epe nla nla lawọn eeyan n ṣẹ fun ọdaju abiyamọ kan to ju…

Nitori Agboọla to dara pọ mọ wọn, awọn ọmọ ẹgbẹ ZLP n binu kuro ninu ẹgbẹ l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ  Ọgọọrọ awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu Zenith Labour Party ni wọn ti binu kuro…

Awọn adigunjale ya wọ otẹẹli n’Ilọrin, eeyan mẹta ni wọn yinbọn fun

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lalẹ ọjọ Aiku, Sannde, ọsẹ yii lawọn adigunjale kan ti wọn to bii…

Tinubu ṣedaro iku Kaṣamu, o ni ko daa kẹnikẹni sọrọ odi si oku ọrun

Aṣiwaju ẹgbẹ oṣelu APC, Bọla Ahmed Tinubu, ti ṣedaro iku to pa Oloogbe Buruji Kaṣamu, ọkan…

Ogoje awọn ọmọbinrin Naijiria ti ha si Saudi Arabia, ẹru ni wọn n fi wọn ṣe

Mejidijnlogoje (138) awọn ọmọ obinrin lati agbegbe gbogbo ni Naijiria ni wọn ti ha si Saudi…

Ọbasanjọ ṣe tẹẹsi Koro, wọn ni baba ko ni Koro o

Ẹbọra Owu, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, naa ti ṣayẹwo Korona o. Aarẹ ilẹ wa tẹlẹ naa ti…

Iru ki waa leleyii, Pasitọ Ajigbọtoluwa tun fun tẹgbọn-taburo loyun l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Iranṣẹ Oluwa lawọn eeyan mọ baba ti ẹ n wo yii si l’Olomoore,…

O ma ṣe o, Buruji ti rele ikẹyin, ọmọ Kasamu ti wọ kaa ilẹ lọ

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Beeyan ba jẹ ori ahun, to ba de ibi isinku ọkunrin olowo nla ati oloṣelu…

Nitori Buruji Kaṣamu, Fayoṣe sọrọ s’Ọbasanjọ, o ni ki baba yee ṣe bii angẹli jare

Gomina Ekiti nigba kan, Ọgbẹni Peter Ayọdele Fayoṣe, ti fibinu sọrọ si aarẹ ana, Oloye Oluṣẹgun…

Toyin Saraki ati iyawo gomina Kwara fun obinrin ti awọ ẹyin oju oun atawọn ọmọ rẹ yatọ n’Ilọrin lowo

Stephen Ajagbe, Ilọrin Akọṣẹmọṣẹ nipa itọju oju awọn ọmọde to wa ni ileewosan ẹkọṣẹ Fasiti Ilọrin,…

Awọn ọlọpaa Eko n wa Adeyẹmi o, wọn lo gun ọkọ ale ẹ lọbẹ pa

Awọn ọlọpaa Eko ni awọn n wa Adekunle Adeyẹmi bayii bayii o, ẹsun ti wọn si…