Aarẹ orilẹ-ede yii nigba kan, Oloye Oluṣẹgun Ọbasanjọ, ti fi oko ọrọ ranṣẹ si oloṣelu ipinlẹ…
Author: Alaroye
O ma ṣe o, Buruji Kasamu ku lojiji!
Agbọ-sọgba-nu ni iku ọkan pataki ninu awọn oloṣelu ipinlẹ Ogun, to tun ti figba kan ṣe…
O ṣẹlẹ, apoogun ku sori aṣẹwo n’Ipaja
Faith Adebọla Ẹka Ọtẹlẹmuyẹ tileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko lawọn ti bẹrẹ iwadii lati mọ bi iku…
Nitori ibo gomina to n bọ l’Ondo, Ọlanusi pada sọdọ Mimiko
Iyiade Oluṣẹyẹ, Akurẹ Igbakeji gomina ipinlẹ Ondo tẹlẹ, Alli Ọlanusi, ti pada sọdọ ọga rẹ tẹlẹ,…
Nitori ẹgunjẹ, ọlọpaa fi idi ibọn gba Taiwo lori, niyẹn ba daku, ko ti i ji saye o
Florence Babasola, Osogbo Ẹsẹ kan aye, ẹsẹ kan ọrun ni Ayọmide Taiwo wa bayii latari bi…
Ijọba Eko ni kawọn akẹkọọ ọlọdun mẹta akọkọ (JSS3), wọle lọjọ kẹwaa, oṣu yii
Faith Adebọla Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹwaa, oṣu kẹjọ ta a wa yii, nijọba ipinlẹ Eko…
Iyawo gomina Kwara fẹẹ ṣeranlọwọ fun Risikatu toun atawọn ọmọ rẹ ni ẹyin oju to yatọ
Stephen Ajagbe, Ilọrin Iyawo Gomina Kwara, Olufọlakẹ Abdulrazaq, ti ṣetan lati ran obinrin kan, Risikatu Azeez,…
Aarẹ Buhari fun Ize-Iyamu ni asia ẹgbẹ APC lati dije sipo gomina l’Edo
Ni ọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii ni Aarẹ Muhammadu Buhari fun oludije sipo gomina nipinlẹ…
O ma ṣe o, ọkọ ajagbe tẹ obinrin to n lọ jẹẹjẹ ẹ pa l’Ekoo
Faith Adebọla Obinrin kan tẹnikẹni ko ti i mọ orukọ ẹ titi di ba a ṣe…
Nibi ti Adedeji ti n gbẹjọ ro lọwọ laṣiiri ẹ ti tu pe ayederu lọọya ni n’Itori
Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ọpọlọpọ ẹjọ ni ọkunrin kan torukọ ẹ n jẹ Adedeji Adelẹkan ti ba awọn…
Nitori Jẹgẹdẹ, Makinde ṣabẹwo ẹlẹẹkeji si Mimiko l’Ondo
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde tun ti ṣepade bonkẹlẹ mi-in pẹlu Dokita Olusẹgun…