Igi ti wọn fẹẹ fi dana lawọn ọmọ yii lọọ ji tawọn ajinigbe fi ji ọgbọ̀n gbe ninu wọn

Adewale Adeoye O kere tan, awọn ọmọde bii ọgbọn ni iroyin ti fidi rẹ mulẹ pe awọn ajinigbe kan ti…

Ẹwọn oṣu mẹrin pẹlu iṣẹ aṣekara ladajọ ju obinrin to faṣọ oṣiṣẹ KAI ya l’Ekoo si

Ẹwọn oṣu mẹrin pẹlu iṣẹ aṣekara ladajọ ju obinrin to faṣọ oṣiṣẹ KAI ya l’Ekoo si Adewale Adeoye Wọn ni…

Adajọ ti ju iyaale ile to da omi gbigbona le ọkọ rẹ lori sẹwọn

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ Abilekọ Khadijah Dauda, tile-ẹjọ Majisireeti kan to wa lagbegbe Kontagora, nijọba ibilẹ Kontagora, nipinlẹ Niger, ni wọn gbe iyaale ile…

Eeyan mẹrin ku marun-un mi-in fara pa nibi ijamba mọto ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Bi eeyan ba jori ahun, omije yoo da loju ẹ l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọjọ…

Ọrọ rirun! Faruq ba ọmọọdun mẹta laṣepọ, o loun fẹẹ fi mọ boya ‘kinni’ oun ṣiṣẹ ni

Ọlawale Ajao, Ibadan Bi wọn ba sọ pe eeyan n sọrọ rirun jade lẹnu,  ta a…

Eemọ ree o! Timothy ji iyawo ile gbe, odidi ọsẹ mẹta lo fi ba a laṣepọ ko too lọ ja a soju titi n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Ọwọ awọn ikọ ẹṣọ alaabo Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọmọkunrin kan, Babalọla Abayọmi…

Iru ki leyii, awọn agbebọn pa baba agbalagba kan atiyawo m’ọnu ile

Monisọla Saka Ninu agbara ẹjẹ ni wọn ti ba baba agbalagba ẹni ọgọrin ọdun (80) kan,…

O ma ṣe o, kọntena kaṣu ja lu mọto oṣiṣẹ fasiti l’Ọṣun, oju-ẹsẹ lo ku

 Florence Babaṣọla, Oṣogbo Obinrin oṣiṣẹ Fasiti Ileṣa, nipinlẹ Ọṣun, ẹni ti a ko ti i mọ…

Ọsẹ yii ni wọn yoo sinku Oluṣọ ti ẹfangẹliisi rẹ pa n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn mọlẹbi Pasitọ Morris Ọlagbaju Fadehan niluu Ileefẹ ti kede Ọjọbọ Tọsidee ọsẹ…

Awọn agbaagba APC Ondo buwọ lu Ayedatiwa, lawọn oludije yooku ba n binu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ko si ani-ani pe inu awọn oludije kan to fẹẹ kopa ninu eto…

O n ru’gboo bọ! Sunday Igboho ti wọ Gani Adams re kootu o

Faith Adebọla Ilu mọ-ọn-ka ajafẹtọọ-ọmọniyan ati ajijangbara ilẹ Yoruba to lewaju awọn to n pe fun…