Ikunlẹ abiyamọ o! Lẹyin ti wọn gun obinrin yii lọbẹ pa tan ni wọn yọ ọkan ẹ lọ

Monisọla Saka Amookunṣeka ẹda kan ti da ẹmi Arabinrin Tina Ileogben legbodo, lẹyin to gun un…

Abiru ki leleyii, baba pa ọmọ ẹ lati fi ṣoogun owo

Adewale Adeoye Ọgbẹni Steady Munda ti n kawọ pọnyin rojọ lagọọ ọlọpaa kan to wa ni agbegbe Chemowa, lorileede…

L’Ọtun-Ekiti, Ọlalẹyẹ fibinu gun ẹni to n la wọn lasiko to n ja pa

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Majisreeti kan to wa l’Ado-Ekiti, ti paṣẹ pe ki okunrin ẹni ọdun…

O ṣẹlẹ, ọmọọdun mẹtadinlogun gbe majele jẹ nitori owo ọga rẹ to ṣe baṣubaṣu

Adewale Adeoye Ileewosan kan to wa niluu Ẹpẹ, nipinlẹ Eko, ni wọn gbe oku gende kan, Oloogbe Ojibe Chibueze, ẹni ọdun mẹtadinlogun, to gbẹmi…

O gbẹnu tan: Shaibu ki ọmọ to bi mọlẹ, o ba a sun karakara

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Kabak, nijọba ibilẹ Mubi-South, nipinlẹ Adamawa, ti mu  baale ile kan, Ọgbẹni Auwal Shaibu, ẹni ọdun mejilelogoji. Ẹsun ti wọn…

Eedi ree o! Mustapha gun ọrẹ ẹ lọbẹ pa l’Ọrẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Kootu Majisireeti to wa lagbegbe Oke-Ẹda, niluu Akurẹ, ti ni ki ọkunrin ẹni…

Ijọba ipinlẹ Ondo fẹẹ gba ẹgbẹrun meji olukọ siṣẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ijọba ipinlẹ Ondo ti kede ipinnu rẹ lati gba ẹgbẹrun meji olukọ si…

Ibo gomina: Eyi lawọn to fẹẹ dupo l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Asiko ta a wa yii ki i ṣeyi to dẹrun rara fun gbogbo…

Eyi lawọn ohun to ṣẹlẹ nibi isinku Olubadan ilẹ Ibadan

Faith Adebọla Ọpọ eeyan ni ipapoda ọba naa ba lojiji, tori wọn o reti ẹ, ti…

Alima yii ti ha o, awọn akẹkọọ ileewe alakọọbẹrẹ mẹta lo ji gbe l’Ekoo

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Ijegun, nipinlẹ Eko, ni iyaale ile kan, Abilekọ Akintọla Alima, ẹni ogoji ọdun, ti wọn fẹsun ijinigbe kan wa bayii. Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kọkanla, oṣu Kẹta,  ni ọwọ awọn agbofinro…

Lori iku Mohbad, awọn ọlọpaa ti ju Prime Boy satimọle o

Adewale Adeoye Titi di asiko ta a n koroyin yii jọ, ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Panti, niluu Yaba, nipinlẹ Eko, ni Ọgbẹni Ibrahim Owodunni, ẹni tawọn eeyan…