Awọn janduku kọ lu Ṣẹgun Oni lasiko ipolongo rẹ l’Ẹfọn-Alaye

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ori lo ko oludije fun ipo gomina ninu eto idibo to n bọ…

Ijọba fofin de ẹgbẹ onimọto, wọn sọ MC Oluọmọ di alaga igbimọ gareeji l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ijọba ipinlẹ Eko ti kede iyansipo Alaaji Musiliu Ayinde Akinsanya tawọn eeyan mọ…

Ẹfun abeedi, baale ile fọ ori ọmọ oṣu kan tiyawo rẹ ṣẹṣẹ bi mọlẹ, niyẹn ba ku patapata

Jọkẹ Amọri Ẹka to n mojuto iwa ọdaran to wa ni Yaba, niluu Eko, ni ileeṣẹ…

Awọn ohun eelo idana ni Lawali lọọ ji tọwọ fi tẹ ẹ n’llọrin

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akilu Lawali ti n ṣẹju pako lahaamọ ajọ ẹṣọ alaabo ṣifu difẹnsi bayii.…

Ogedengbe yoo ṣẹwọn ọdun meji ataabọ, ẹni to fi mọto gba ti larun ọpọlọ l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Nitori pe o wa ọkọ lai ni lansẹnsi, ile-ẹjọ Majisreeti kan to wa…

Kinni ọkọ mi ko ṣiṣẹ daadaa mọ, adajọ, ẹ tu wa ka-Blessing

Adewumi Adegoke Ile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa niluu Igando, nipinlẹ Eko, ni obinrin aṣerun-lọṣọọ kan, Blessing…

Ẹ pada sinu ẹgbẹ APC, Lai Muhammed rọ awọn alatilẹyin rẹ ni Kwara

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Minisita to n ri si ibanisọrọ ati aṣa nilẹ yii, Lai Muhammed, ti…

Awọn eleyii yoo dọgbọn bii ero, ni wọn yoo ba gba owo ati kẹkẹ NAPEPlọwọ ẹni to ni i

Ọrẹoluwa Adedeji Ọjọ gbogbo ni tole, ọjọ kan bayii ni tolohun, bẹẹ lọrọ ri fun ọkunrin…

Sikiru binu ṣa baba ẹ pa l’Abẹokuta, tori tiyẹn ni ko lọọ waṣẹ ṣe

Gbenga Amos, Abeokuta Kayeefi lọrọ ọmọkunrin ẹni ọdun mẹtadinlọgbọnkan, Sikiru Ibrahim. Baba to bi i lọmọ…

Nibi ti awọn ale Pasitọ Isaac ti n lu iyawo ẹ lọmọ oṣu mẹjọ to gbe lọwọ ti ku n’Ijẹbu

Gbenga Amos, Abẹokuta Jẹbẹtẹ ti gbọmọ le ojiṣẹ Oluwa ẹni aadọta ọdun kan, Pasitọ Isaac Akinbọla,…

Grassroots 37 rọ Ọṣinbajo lati waa dupo aarẹ, wọn bun un ni ẹgbẹrun lọna ẹẹdẹgbẹta Naira

Jọkẹ Amọri Awọn ẹgbẹ kan ti wọn pera wọn ni ‘Grassroots 37 fun Ọṣinbajo’, ti rọ…