O ma ṣe o, ọsẹ kan lẹyin ti oṣere tiata yii ṣọjọọbi ni wọn ba oku ẹ loteẹli kan

Faith Adebọla  “Kai, aye ma nika o! Lọjọ kejila, oṣu Kẹta, ọdun to kọja, a ṣayẹyẹ…

Ile-ẹjọ ni ki wọn yẹgi fun Tunmiṣe to pa lanledi rẹ l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lẹyin ọdun mẹta to ti pa iya onile rẹ l’Ado-Ekiti, ile-ẹjọ giga kan…

Ọga ọlọpaa patapata bẹ awọn ọmọọṣẹ rẹ: A maa san ẹkunwo fun yin, ẹ ma daṣẹ silẹ o

Adewumi Adegoke Latari ipinnu awọn ọlọpaa ilẹ wa lati bẹrẹ iyanṣẹlodi nitori ẹkunwo ti wọn n…

Mo fa ara mi kalẹ lati yọ ọkọ Naijiria to fẹẹ doju de yii lọwọ ewu – Atiku

Faith Adebọla Igbakeji aarẹ ilẹ wa nigba kan, Alaaji Atiku Abubakar, ti kede pe toun ba…

Ti mo ba di aarẹ, mi o ni i yan ẹnikẹni tọjọ ori ẹ ba ju marundinlogoji lọ sipo – Saraki

Faith Adebọla  “Ọdọ ni gbogbo awọn to maa wa ninu igbimọ iṣakoso mi maa jẹ, ti…

‘Awọn alawo ti wọn fẹhonu han ni Fasiti Ifẹ ki i ṣe ara wa o’

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Awọn adari ati ọmọ ẹgbẹ ẹlẹsin abalaye, Traditional Religion Worshippers Association (TRWASO), ti…

Kọmiṣanna ọlọpaa Ogun: Mọto ọlọpaa to ko irẹsi tawọn kọsitọọmu gba lọwọ awọn onifayawọ ki i ṣe tiwa o

Gbenga Amos, Abẹokuta Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ogun ti ni inu awọn ko dun si ọrọ kan…

Tori bile-ẹjọ ṣe wọgi le isọri kẹrinlelọgọrin ofin eto idibo, awọn aṣofin pẹjọ ko-tẹ-mi-lọrun

Faith Adebọla  Kaka kewe agbọn dẹ, niṣe lo n le koko si i lọrọ awuyewuye lori…

Ẹni ti Buahri ba fọwọ si lati dupo alaga la maa ṣatilẹyin fun-Awọn gomina APC

Jọkẹ Amọri Ẹgbẹ awọn gomina to jẹ ti ọmọ ẹgbẹ oṣelu APC ti fi ipinnu wọn…

Kayeefi ree o, lọjọ keji ti kọmiṣanna yii darapọ mọ ẹgbẹ APC lati PDP lọmọ rẹ fo ṣanlẹ to ku ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ keji ti kọmiṣanna tẹlẹ, to tun jẹ alaga igbimọ alakooso ni ileewe…

Hausa ti lanlọọdu gba sile gun un pa nitori ọrọ ti ko to nnkan n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Titi ta a fi pari akojọpọ iroyin yii ni wọn ṣi n wa…