Awọn agbebọn ji oṣiṣẹ Oloye Ọbasanjọ mẹta gbe l’Ọbafẹmi Owode

Titi di ba a ṣe n sọ yii ni wọn ṣi n wa awọn oṣiṣẹ aarẹ…

Olukọ Fasiti Ifẹ ti wọn da duro ni: Ko si ẹri pe mo huwa ti ko dara si akẹkọọ-binrin kankan

Florence Babaṣọla Olukọ Fasiti Ọbafẹmi Awolọwọ, Ileefẹ, ti awọn ọmọ igbimọ oluṣakoso ileewe naa da duro…

O ṣẹlẹ, wọn ni ole ti ji faili ẹjọ awọn ọmọ Sunday Igboho gbe o

L’Ọjọruu ọsẹ yii ni esuke wọ rara ni kootu giga ilu Abuja, nibi ti wọn ti…

DSS fẹsun afẹmiṣofo kan awọn ọmọọṣẹ Igboho meji to wa lọdọ wọn

Ikọ ọtẹlẹmuyẹ DSS ti fẹsun afẹmiṣofo kan meji ninu awọn ọmọ ẹyin Sunday Igboho, awọn naa…

Wọn fọmọ ọdun mọkandinlogun lọkọ ni tipatipa l’Adamawa, lo ba gun ọkunrin naa pa

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  Atimọle ọlọpaa ni ọmọbinrin ẹni ọdun mọkandinlogun kan ti wọn pe orukọ ẹ…

Okuta ni Oluwapelumi la mọ Jafaru lori tiyẹn fi ku, ladajọ ba ni ko maa lọ sẹwọn l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Ile-ẹjọ Majsitreeti kan to wa niluu Ado-Ekiti ti paṣẹ l’Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ yii,…

Wọn ni arun Kọlẹra pa eeyan mẹẹẹdọgbọn l’Ogun, ṣugbọn ijọba ni irọ ni

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Lọjọ Sannde ọsẹ yii, Kọmiṣanna eto ilera nipinlẹ Ogun, Dokita Tomi Coker, fi…

Ademọla Adeleke balẹ sipinlẹ Ọṣun, o ni ki  Oyetọla maa palẹ ẹru rẹ mọ l’Abere

Florence Babaṣọla Lẹyin asiko diẹ to lo loke-okun lati fi fimọ kun imọ, Sẹnetọ Ademọla Adeleke…

Gomina Oyetọla ko ẹṣọ Amọtẹkun jade l’Ọṣun

Florence Babaṣọla Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ni Gomina ipinlẹ Ọṣun, Adegboyega Oyetọla, ṣe ikọjade awọn eeyan ọtalelọọọdunrun-un…

Fasiti Ifẹ le Dokita Mosọbọlaje danu, wọn lo tasẹ agẹrẹ si akẹkọọ-binrin kan

Florence Babaṣọla Ninu ipinnu rẹ lati ma ṣe faaye gba iwa ṣiṣe awọn akẹkọọ-binrin baṣubaṣu, hihalẹ…

Agbẹjọro bẹ Ọọni lati ba Buhari sọrọ lori awọn ọmọọṣẹ Sunday Igboho tawọn DSS kọ lati fi silẹ

Faith Adebọla Arọwa ti lọ sọdọ Ọọniriṣa, Ọba Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja Keji, lati da si ọrọ…