Awọn agbebọn ti tun ji agbẹ mi-in gbe lọ ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Aje, Monde, ọṣẹ yii, ni awọn agbebọn to dihamọra pẹlu ibọn ati…

Akọwe ẹgbẹ APC l’Ọṣun, alaga TOP atawọn marun-un mi-in foju bale-ẹjọ

Florence Babaṣọla Akọwe ẹgbẹ oṣelu APC nipinlẹ Ọṣun, Rasaq Ṣalinṣile, ati Alagba Lọwọ Adebiyi to jẹ…

Ipinlẹ Ọṣun padanu eeyan mẹtala sọwọ arun Koronafairọọsi laarin ọsẹ kan

Florence Babaṣọla Ijọba ipinlẹ Ọṣun ti kegbajare pe ki gbogbo awọn olugbe ilu naa ma ṣe…

Awọn agbebọn kọ lu ileeṣẹ ologun ni Kaduna, wọn paayan meji, wọn tun ji ṣọja kan gbe sa lọ

Jọkẹ Amọri Iyalẹnu lo ṣi n jẹ fun gbogbo awọn ti wọn gbọ pe awọn agbebọn…

Gende mẹtadinlogoji dero ahamọ EFCC n’Ibadan, wọn lọmọ ‘Yahoo’ ni wọn

Faith Adebọla Teeyan ba ri bi wọn ṣe to wọn sori ila niwaju ileeṣẹ ajọ to…

Ile-ẹjọ yẹ aga mọ Secondus, alaga ẹgbẹ PDP, nidii

Faith Adebọla  Ile-ẹjọ giga kan to fikalẹ siluu Port-Harcourt, nipinlẹ Rivers, ti paṣẹ pe ki alaga…

Sẹnetọ Biyi Durojaiye ti ku o

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Sẹnetọ Biyi Durojaye, ẹni to ṣoju ẹkun Ila-Oorun ipinlẹ Ogun nileegbimọ aṣofin agba…

Mi o ṣoṣelu mọ, mo ti fi silẹ fawọn ọdọ-Ladọja

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Oloye Rashidi Ladọja, gomina ipinlẹ Ọyọ nigba kan, ti sọ pe oun ki…

Ọwọ tẹ Desmond atọrẹ ẹ, ọmọ ọdun mẹjọ ni wọn ji gbe n’Ipaja

Faith Adebọla, Eko Ọrẹ ki i ya ọrẹ lawọn mejeeji, afaimọ si lọrẹ wọn ko ni…

Owo burẹdi n goke, ṣugbọn awọn to n ṣe e ni yoo tun wọn ju bẹẹ lọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Pẹlu bo ṣe jẹ pe owo burẹdi ti goke si i kaakiri ni…

Abilekọ Victoria, iyawo Aguiyi-Ironsi, jade laye lẹni ọdun mẹtadinlọgọrun-unu

Jọke Amọri Abilekọ Victoria  Aguiyi-Ironsi to jẹ iyawo olori orileede Naijiria tẹlẹ, Ọgagun J.T.U Aguiyi-Ironsi, ti…