2023: Ilẹ Yoruba ṣetan lati gbajọba, ọrọ ku sọwọ Tinubu, Fayẹmi – ARG

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ Afẹnifẹre Renewal Group (ARG) ti sọ pe ilẹ Yoruba ṣetan lati gba…

Magu, olori EFCC tẹlẹ, ti tun n kawọ sẹyin rojọ

Loni-in ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹtala oṣu keje, ọdun 2020, Ọgbẹni Ibrahim Magu ti i ṣe…

Eeyan marundinlaaadọrin ko arun Korona lọjọ kan ṣoṣo nipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Abamẹta, Satide to kọja, nikan ṣoṣo, eeyan marundinlaaadọrin (65) lo ko arun Korona…

Awọn oluranlọwọ igbakeji gomina Kwara ti ko arun Korona

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lẹyin ọjọ diẹ ti arun Korona pa olori oṣiṣẹ gomina nipinlẹ Kwara, Aminu Adisa…

Lẹyin ọjọ mẹrin to dawati, ileeṣẹ panapana ri oku Abdullateef ninu odo n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lẹyin ọjọ mẹrin ti wọn ti n wa Abdulwaheed Abdullateef, ẹni ọdun mẹrindinlọgbọn,…

Ọbaladi Afọn tun waja, lọjọ keji ti Olu Imaṣayi papoda

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọbaladi ti Afọn, nijọba ibilẹ Imẹkọ-Afọn, nipinlẹ Ogun, Ọba Busari Adetọna, naa ti…

Lẹyin ọsẹ mẹta ti Ajimọbi ku ni kọmiṣanna rẹ ku sinu ijamba mọto

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ mẹta ti gomina ipinlẹ Ọyọ tẹlẹ, Sẹnetọ Abiọla Ajimọbi ku, ọkan…

Ko sẹni to yọ orukọ mi kuro ninu awọn oludije – Akeredolu

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ondo, Rotimi Akeredolu, ti ni ko si ootọ ninu ahesọ to n…

Ibanikẹdun n rọ bii ojo nipinlẹ Ogun, ọba mẹta lo waja laarin ọsẹ kan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bo tilẹ jẹ pe agbalagba ni wọn, ti ko si eyi to ṣanku…

Lẹyin ọjọ mẹwaa nigbele, akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun bọ lọwọ arun Koronafairọọsi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Akọwe ijọba ipinlẹ Ọṣun, Ọmọọba Wọle Oyebamiji, ti jajabọ lọwọ arun Koronafairọọsi bayii.…

Wọn ṣi n wa awọn eeyan tawọn ajinigbe ji gbe lọ l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lalẹ ọjọ Ẹti, Furaidee, lawọn ajinigbe kan ti wọn to mẹwaa ya bo…