Ijọba Eko ni kawọn akẹkọọ ọlọdun mẹta akọkọ (JSS3), wọle lọjọ kẹwaa, oṣu yii 

Faith Adebọla Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹwaa, oṣu kẹjọ ta a wa yii, nijọba ipinlẹ Eko…

Iyawo gomina Kwara fẹẹ ṣeranlọwọ fun Risikatu toun atawọn ọmọ rẹ ni ẹyin oju to yatọ

Stephen Ajagbe, Ilọrin Iyawo Gomina Kwara, Olufọlakẹ Abdulrazaq, ti ṣetan lati ran obinrin kan, Risikatu Azeez,…

Aarẹ Buhari fun Ize-Iyamu ni asia ẹgbẹ APC lati dije sipo gomina l’Edo

Ni ọjọ Ẹti, Furaidee, opin ọsẹ yii ni Aarẹ Muhammadu Buhari fun oludije sipo gomina nipinlẹ…

Alaga ẹgbẹ oṣiṣẹ sọrọ nipa akẹkọọ fasiti ti maṣinni ge si wẹwẹ n’Ibadan (Fidio)

O ma ṣe o, ọkọ ajagbe tẹ obinrin to n lọ jẹẹjẹ ẹ pa l’Ekoo

Faith Adebọla Obinrin kan tẹnikẹni ko ti i mọ orukọ ẹ titi di ba a ṣe…

 Nibi ti Adedeji ti n gbẹjọ ro lọwọ laṣiiri ẹ ti tu pe ayederu lọọya ni n’Itori

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ọpọlọpọ ẹjọ ni ọkunrin kan torukọ ẹ n jẹ Adedeji Adelẹkan ti ba awọn…

Nitori Jẹgẹdẹ, Makinde ṣabẹwo ẹlẹẹkeji si Mimiko l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde tun ti ṣepade bonkẹlẹ mi-in pẹlu Dokita Olusẹgun…

Adajọ ti ju Adebọwale ọlọkada to fipa ba ọmọ ọdun mẹtala sun n’Ileefẹ sẹwọn

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ile-ẹjọ Majisreeti kan niluu Ileefẹ, ti ju Adebọwale Gboye, ẹni ọgbọn ọdun, sẹwọn…

Tori wọn ṣẹ sofin Korona, ile-ẹjọ ni ki Naira Marley sanwo itanran

Faith Adebọla Owo itanran ẹgbẹrun lọna ọgọrun-un meji naira (N200,000) nile-ẹjọ to n gbọ awọn ẹsun…

O ṣẹlẹ! Asẹyin tilu Isẹyin rọ meji ninu awọn ijoye rẹ loye 

Ọlawale Ajao, Ibadan Asẹyin tilu Isẹyin, Ọba Abdul Ganiy Adekunle Salawu, ti rọ meji ninu awọn…

Ile Arugbo: Ile-ẹjọ ti ni ijọba Kwara le kọle sori ilẹ awọn Saraki o

Stephen Ajagbe, Ilorin L’Ọjọbọ, Tọsidee, oni yii, ni ile-ẹjọ giga kan ni ipinlẹ Kwara ti fun…