Olusẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Ọkan ninu awọn oludije ibo abẹle ẹgbẹ APC to waye lọsẹ to kọja,…
Category: Ìròyìn
Ipinlẹ Ogun ni Mumini ti ji owo lanledi rẹ, Oṣogbo lọwọ awọn Amọtẹkun ti tẹ ẹ
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọwọ awọn ikọ Amọtẹkun ipinlẹ Ọṣun ti tẹ ọmọkunrin kan, Mumini Saheed, ẹni…
O ma ṣe o: Baba Onipuulu yii si binu para ẹ ni Saabo, Eko
Ọkunrin oniṣọọbu puulu (pool) kan, nibi tawọn eeyan ti n ta tẹtẹ ati baba-ijẹbu ninu ọja…
Jẹgẹdẹ ti sọrọ, o ni ki Akeredolu maa ko ẹru ẹ kuro nile ijọba
Ẹni ti ẹgbẹ PDP fa kalẹ lati du ipo gomina ipinlẹ Ondo ninu ibo ti wọn…
Haa, awọn ọlọpaa ti wọn fẹẹ gba ẹgunjẹ si jẹ ki Adisa fi mọto pa obinrin yii
Njẹ ẹ gbọ pe wọn ti pa Stella Okolie, obinrin olukọni kan ni ile-ẹko giga ti…
Eyi lawọn fọto isinku Tolulọpẹ Arotile
Lonii, Ọjọbọ, Tọsidee, ni wọn sinku Tolulọpẹ Arotile, ọmọbinrin afẹronpileeni-jagun akọkọ ninu iṣẹ ọmọ-ogun ofurufu nilẹ…
Aarẹ wa balẹ si Bamako, ni Buhari ba bo imu ẹ pinpin
Aarẹ ilẹ wa, Ọgagun Muhammadu Buhari, ti balẹ si Bamako, lorileede Mali, nibi ti oun atawọn…
O ṣẹlẹ, awọn aṣofin fẹẹ ran minisita yii lẹwọn
Olori ile-igbimọ aṣoju-ṣofin, Họnọrebu Fẹmi Gbajabiamila, ti ni ẹwọn n run nimu Minisita fun ọrọ agbegbe…
O digbooṣe, akọni obinrin wọ kaa ilẹ lọ
Wọn ti sinku Tolulọpẹ Arotile sibi ti wọn maa n sin awọn akọni si ni itẹkuu…
Baba ti wọn mu nitori wọn lọmọ ẹ n ja n’Ibadan ti ku sọdọ awọn ọlọpaa o
Ijẹsan-an lawọn ọlọpaa ti mu un, ni Ọjọruu, Wẹsidee, ọsẹ to kọja. Wọn mu baba naa,…
O ma ṣe o! Eto isinku Tolulọpẹ ti bẹrẹ niluu Abuja
Lọwọlọwọ yii, wọn ti gbe oku ọmọdebinrin to jẹ ẹni akọkọ to n fi baalu-agbera-paa jagun…