Miliọnu mẹta eeyan forukọ silẹ fun N-Power

Ijọba apapọ ti kede pe awọn to le ni miliọnu mẹta lo ti forukọ silẹ fun…

Awọn ileewe Eko yoo ṣi loṣu to n bọ

Ijọba ipinlẹ Eko ti kede pe awọn ileewe ipinlẹ naa yoo ṣi lọjọ kẹta, oṣu to…

Ijọba ṣeleri lati ṣatunṣe ọna Kaiama si Baruten

Stephen Ajagbe, Ilọrin Abẹnugan ile igbimọ aṣofin ipinlẹ Kwara, Ọnarebu Yakubu Danladi-Salihu, ti fi da awọn…

Ijamba ina ba dukia jẹ nile itaja nla niluu Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilọrin Ṣọọbu mẹta ọtọọtọ nile itaja nla oniyara mẹrinla kan, Abdulsalam Shopping Complex, lọna…

Oju ole ree! Nibi ti Isiaka ti lọọ ji pọmpu omi lọwọ ti tẹ ẹ n’Ilọrin

Stephen Ajagbe, Ilorin Awọn araadugbo Adeta, niluu Ilọrin, ti fa afurasi ẹni ọdun marundinlọgbọn kan, Isiaka, tọwọ…

Awọn ti mi o ba rowo ji nile wọn ni mo maa n ba iyawo tabi ọmọọdọ wọn lo pọ – Adeniyi

Faith Adebọla, Eko “Ẹ wo o, lati oṣu kin-in-ni, ọdun 2019, lemi ti n digunjale, mi…

Akẹkọọ Fasiti Ilọrin rẹwọn oṣu mẹsan-an he fẹsun jibiti

Stephen Ajagbe, Ilorin Adajọ Sikiru Oyinloye tile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, ti sọ akẹkọọ…

Ọọni yoo gbe igbesẹ lori iwọde tawọn oṣiṣẹ-fẹyinti ṣe nitori Oyetọla

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọọni tilu Ileefẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, ti ṣeleri lati da si ọrọ…

Ajọ iṣọkan agbaye fẹẹ kọ ẹgbẹrun lọna aadọta ile s’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹka ajọ iṣọkan agbaye to n ri si iṣẹ akanṣe (UNOPS) ti bẹrẹ…

Koronafairọọsi: Ofin konilegbele n palẹmọ diẹdiẹ l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lalẹ ọjọ Iṣẹgun, Tusidee to kọja, ni Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti kede…

Ọrọ yii ṣi maa dija: Wọn ti gba APC lọwọ Tinubu o

Nigba ti alaga igbimọ awọn gomina ẹgbẹ APC, Atiku Bagudu to tun jẹ gomina ipinlẹ Kebbi…