Eyi ni awọn ijọba ibilẹ ti PDP, APC ti bori

Florence Babaṣọla

Ijọba ibilẹ mẹtadinlogun, ninu ọgbọn ni Ademọla Adeleke to ṣẹṣẹ jawe olubori ninu eto idibo Ọṣun ti wọn di lọjọ kẹrindinlogun, Oṣu Keje, ọsun 2022 yii, ti rọwọ mu.

Awọn ijọba ibilẹ naa niwọyi:Atakunmọsa West, Boluwaduro, Ẹdẹ North, Ẹdẹ South, Egbẹdọrẹ, Ejigbo, Ifẹ North, Ifẹlodun, Ila, Ileṣa West, Irẹpọdun, Obokun ati Odo Ọtin, Ọlọrunda Orolu, Oriade ati Oṣogbo.

Nigba ti APC wọle lawọn ijọba ibilẹ: Atakunmọsa East, Ayedaade, Ayedire, Boripẹ, Ifẹ Central, Ifẹ South, Ifẹ East, Ifẹdayọ, Ileṣa East, Irewọle, Iṣọkan, Iwo ati Ọlaoluwa.

Leave a Reply