FIDIO: Wọn dana sun mọto BRT l’Ekoo

Awọn eeyan ti inu n bi nitori bi awọn ṣọja ṣe yinbọn pa awọn ọdọ kan lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọsẹ yii, ti dana sun mọto akero ọlọpọ eeyan to jẹ tijọba ipinlẹ Eko, BRT.

Ileeṣẹ ọkọ naa to wa ni Oyingbo ati Oṣodi ni wọn sọna si, ti ọpọ mọto si ti jo deeru.

Leave a Reply