Ọjọ Ẹti, ni wọn fi idajọ Sunday Igboho si

Ọjọ Ẹti, Furaidee, ọla ni ile-ẹjọ giga to jokoo gbọ ẹjọ naa ni orileede Olominira Benin sun igbẹjọ Sunday Igboho si.

Leave a Reply