Pẹlu bi b’awọn Taliban ṣe gbajọba ni Afghanistan, inu ewu nilẹ Afrika wa-Buhari

Faith Adebọla Aarẹ ilẹ wa, Ajagun-fẹyinti Muhammadu Buhari ti sọ pe bawọn ajagunta Taliban ṣe gbajọba…

Bi nnkan ba n lọ bo ṣe n lọ yii, ọjọ kan la maa ji torileede yii maa dawati– Fani-Kayọde

 Faith Adebọla, Eko  Minisita feto igbokegbodo ọkọ ofurufu nigba kan, Fẹmi Fani-Kayọde, ti bẹnu atẹ lu…

FIDIO: Ẹ GBÀ MÍ LỌ́WỌ́ ÌJỌBA ÈKÓ, MI Ò NÍ ÀRÙN KÒRÓNÀ, WỌN Ò SÌ JẸ́ KÍ N LỌ

Aṣofin Kwara fẹẹ gba ẹbun ironigbara to fun ọmọlẹyin ẹ, o ni ko ṣatilẹyin foun mọ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Aṣofin kan nipinlẹ Kwara,  Họnọrebu Razaq Owolabi, to n ṣoju Share/Oke-Ode, ti n…

Orileede Italy lobinrin yii dagbere, aṣe egboogi oloro lo fẹẹ gbe lọ sọhun-un

Faith Adebọla, Eko Bi gbogbo aye ṣe n dagbere irinajo ilẹ okeere fawọn eeyan wọn naa…

Awọn agbebọn tun ji ọmọleewe mẹẹẹdogun ko ni Zamfara, wọn yinbọn pa ọlọpaa ati ọlọdẹ meji to n ṣọ wọn

Faith Adebọla Ojumọ ire kọ lo mọ fọpọ awọn obi ati mọlẹbi awọn akẹkọọ kọlẹẹji ẹkọ…

Alaba yoo pẹ lẹwọn o, ọkunrin oniṣowo kan lo lu ni jibiti  l’Afao-Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Yoruba bọ wọn ni ọjọ gbogbo ni ti ole, ṣugbọn ọjọ ṣoṣo ni…

O ma ṣe o, aṣofin ipinlẹ Ondo ku lojiji

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ṣe ni ibanujẹ dori awọn eeyan ilu Akurẹ  kodo latari iku ọmọ ileegbimọ…

Eyi lohun tawọn alaṣẹ ileewe TASUED sọ lori akẹkọọ wọn to binu para ẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Nigba ti iroyin iku Oshọkọya Deborah Ayọmikun gbode kan lọjọ kọkanla, oṣu kẹjọ…

Awọn agbebọn ji ọmọ oṣiṣẹ ọfiisi Buhari gbe ni Kaduna

Faith Adebọla Niṣe ni iṣẹ ijinigbe awọn agbebọn tubọ n gogo si i nipinlẹ Kaduna lasiko…

Ajalu buruku leleyii o, ṣọja mọkanlegun ti wọn ṣẹṣẹ wọṣẹ ologun ku ninu ijamba ọkọ

Faith Adebọla Alukoro ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Jigawa, Lawan Shiisu Adam, ti fidi ẹ mulẹ pe ko…