Nitori ede-aiyede to ni pẹlu awọn ẹbi rẹ, Bamidele ‘ṣe bii ọkunrin’ ni Ìgbúròwò

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Iṣẹlẹ iku ọkunrin ẹni ọdun mejidinlọgọta kan, Bamidele Ọmọlayọ, ẹni ti wọn ṣalaabapade…

Nibi ti wọn ti n ṣe pati lọwọ lawọn amunifọba ti mu ọmọ ọlọjọọbi l’Ekoo

Adewale Adeoye Ọmọ ọlọjọọbi kan ti ṣe pati daran bayii, ọjọ ti iba si jẹ ọjọ…

Awọn araalu maa bẹrẹ si i jẹgbadun iṣẹ idagbasoke ti Aarẹ Tinubu n ṣe- Ganduje

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Pẹlu bawọn eeyan orileede yii ṣe n figba gbogbo kigbe tantan pe ilu…

Philippines lọwọ ti tẹ ọmọ Naijiria ti wọn n wa lorileede Amẹrika

Adewale Adeoye Ni bayii, inu ahamọ awọn agbofinro orileede Amẹrika, ni ọmọ Naijiria kan, Ọgbẹni Ahmed…

Erin wo! Baba Agbako onitiata ti jade laye

Jọkẹ Amọri Ọga agba ninu awọn oṣere, to si tun dagba ju lọ ninu awọn onitaita…

Ẹgbẹ APC ni ki Ọgbẹni Arẹgbẹṣọla lọọ rọọkun nile, eyi lohun ti wọn lo ṣẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ẹgbẹ osẹlu All Progressives Congress (APC), nipinlẹ Ọṣun, ti sọ pe ki minisita…

Nitori ifẹhonuhan awọn Musulumi, eyi lohun ti Ṣọun Ogbomọṣọ ṣe

Ọlawale Ajao, Ibadan Nitori ifẹhonuhan ti awọn Musulumi ṣe niluu Ogbomọṣọ, latari bi wọn ṣe fẹẹ…

NNPCL ti tun fi kun owo epo bẹntiroolu, eyi niye ti wọn n ta a bayii

Ọrẹlouwa Adedeji Lẹyin bii ọsẹ mẹta ti wọn ṣẹ bẹẹ gbẹyin, ileeṣẹ to n ri sọrọ…

Dangote sọ fun NNPCL: Ẹ ma lọ silẹ Okeere lọọ ra bẹntiroolu mọ, epo pọ nilẹ yanturu nileeṣẹ wa

‘’Ohun ti ẹ n wa lọ si Ṣokoto, ti wa lapo ṣokoto yin, ko nilo kẹ…

Oṣere ilẹ wa, Nkechi Blessing, tọrọ aforiji ni gbangba ni Toronto, lorileede Canada

Jọkẹ  Amọri Yoruba ni bi ẹlẹjọ ba mọ ẹjọ rẹ lẹbi, ko ni i pẹ lori…

Wọn ti gbe Bobrisky digbadigba lọ sileewosan o, wọn lara rẹ ko ya gidigidi

Adewale Adeoye Ki i ṣe iroyin mọ pe wọn ti fọwọ ofin mu gbajumọ ọmọ jayejaye…