Wọn tun n bakan bọ: Wọn ni ọga ọlọpaa pata ni yoo maa dari eto Amọtẹkun o

O da bii pe gbogbo eto yoowu ti awọn gomina ilẹ Yoruba ba ṣe lori ikọ…

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Fayẹmi l’Ekiti pẹlu awọn ọrẹ rẹ Nigba miiran, awọn oloṣelu fẹran ẹtan, wọn yoo si maa…

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Kin ni ijọba Buhari yii fẹ gan-an? Ijọba Naijiria gbe ofin tuntun kan jade, ofin to…

Lẹyin ti Taoreed gbowo ni banki, wọn yinbọn pa a, wọn tun gbe owo ẹ sa lọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Ẹkun lawọn ti ko le mu iṣẹlẹ naa mọra bu si nigba ti…

Fidio: Olori ẹgbẹ Asọludẹrọ to mu Sunday, apaayan Akinyẹle, ti ṣalaye bi wọn ṣe mu un fun ALAROYE

Ọlawale Ajao, Ibadan  

Ọjọgbọn Fọlaṣade Ogunṣọla di obinrin akọkọ ti yoo di Adele ọga agba Fasiti Eko

Faith Adebọla, Eko Ọjọgbọn Fọlaṣade Tolulọpẹ Ogunṣọla ti jawe olubori ninu ibo ti igbimọ alakooso Fasiti…

Kọmiṣanna feto Ilera l’Ekoo, Akin Abayọmi, ti ni Korona

Faith Adebọla, Eko Owe Yoruba kan lo sọ pe ‘Oju ti oniṣegun t’ọmọ ẹ ku lọsan-an,…

 Arun Korona tun pa eeyan meji ni Kwara, ijọba ibilẹ mọkanla lo ti tan de

Stephen Ajagbe, Ilọrin Eeyan meji mi-in ni arun Korona tun gbẹmin wọn mọjumọ ọjọ Aje, Mọnde,…

Sunday to n pawọn eeyan l’Akinyẹle ti jẹwọ o: Eyi ni bi mo ṣe sa mawọn ọlọpaa lọwọ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Gbajugbaja afurasi ọdaran to wa loju ọpọn bayii, Sunday Shodipẹ, ẹni ti gbogbo…

Ẹwọn n run nimu Ọmọlade, iya onirẹsi lo lu ni jibiti owo nla n’Ileefẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Apo irẹsi ọgọrun-un ni wọn ni Oyetoro Ọmọlade gba lọwọ Alhaja Eluwọle Sẹrifat…

Ijọba fẹẹ ka iye awọn eeyan to talaka ju lọ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Ọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii ni eto kika iye eeyan ti oṣi ati…