Alaye iya Abdulwasiu, ọkọ obinrin toju ẹ yatọ n’Ilọrin (Fidio)

Ọlọrun oju ẹ da, Ọba to tobi ni ọ o!

Bi mo ṣe fẹẹ jade nile ni mo pade Sẹki, mo fẹẹ maa sọ pe ṣe…

Iku Buruji Kashamu: Idaamu ti ba awọn oloṣelu o

Ki i ṣe e pe ọkan wọn le naa tẹlẹ, ṣugbọn iku to waa pa ọkunrin…

Konikaluku fidi mọle, ko ni i si ipejọpọ fun ayẹyẹ Ọṣun Oṣogbo- Adebisi

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Latari bi awọn to n lugbadi arun Korona ṣe n pọ si i…

Ọwọ tẹ awọn ọmọ ‘yahoo’ mejilelọgbọn niluu Ogbomọṣọ, akẹkọo fasiti lo pọ ninu wọn

Owe Yoruba kan lo sọ pe ọjọ gbogbo ni tole, ṣugbọn ọjọ kan bayii ni tolohun.…

Korona tun pa Alaga Ijọba Ibilẹ Idagbasoke Onigbongbo

Ọkan ninu awọn alaga ijọba ibilẹ nipinlẹ Eko, Ọgbẹni Francis Babatunde Oke, to jẹ alaga Ijọba…

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Nibo lawọn eeyan yii wa o Nigba ti wọn gbe fidio kan jade lọsẹ to kọja…

O ṣoju mi koro (Apa kin-in-ni)

Ẹni ba moju baba yii, ẹ jẹ yaa ba a sọrọ Ni ọjọ kọkandinlogun, oṣu kọkanla,…

Wọn fẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba, wọn lo gbowo lọwọ awọn afẹmiṣofo

Wọn ti fi ẹsun buruku kan Purofẹsọ ọmọ Yoruba kan o, Ishaq Akintọla ti yunifasiti LASU,…

Wahala Ire-Ekiti: Awọn ọlọpaa ni ki i ṣe ọta ibọn awọn lo pa awọn to ku

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti kede pe ọta ibọn kọ lo pa awọn…

Sanwo-Olu ni yoo ṣaaju ipolongo ibo Akeredolu l’Ondo

Bi gbogbo nnkan ba lọ bo ṣe yẹ, Satide, ọjọ kẹẹẹdogun, oṣu yii, ni  ẹgbẹ oṣelu…