Eyi lorukọ awọn ti yoo dije dupo gomina Ondo ti ajọ INEC fi sita

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Iyalẹnu nla lo jẹ fawọn eeyan ipinlẹ Ondo nigba ti wọn ri orukọ…

Onibaara lu alagbe ẹgbẹ ẹ pa l’Ekoo, o lo n yọju wo abẹ oun nigba toun n tọ

Faith Adebọla, Eko  Iyalẹnu gbaa niṣẹlẹ aburu kan to waye lagbegbe Victoria Island, l’Ekoo, yii jẹ…

Lẹyin ọjọ mọkanla, Fayẹmi bọ lọwọ Korona

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lẹyin ọjọ mọkanla ti Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti ti ni arun Koronafairọọsi,…

Nitori  ibo Ondo to n bọ, Akeredolu ṣabẹwo si Tinubu

Ibo ti won yoo di ni ipinlẹ Ondo lati yan gomina tuntun ko ju oṣu meji…

Awọn Boko Haram kọ lu gomina, diẹ lo ku ki wọn mu un

Ọlọrun lo yọ Gomina Ipinlẹ Borno o. Gomina Babagana Zulum n pin ounjẹ kaakiri awọn adugbo…

Wọn ni ọdẹ ori lo n yọ ṣọja to yinbọn pa ọga ẹ ni Borno lẹnu

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ṣọja kan ti ileeṣẹ ologun ilẹ wa ko darukọ rẹ ti yinbọn pa…

Maṣinni ti wọn fi n ṣe ọṣẹ lo ge akẹkọọ Fasiti Ibadan yii si wẹwẹ nibi to ti n ṣiṣẹ

Titi di ba a ṣe n sọ yii lawọn eeayn ṣi n tara ikunlẹ abiyamọ lori…

Ẹ woju Pasitọ Adetokunbọ to jiiyan gbe ninu ṣọọṣi ẹ ni Ṣagamu, o ni koun le rowo ẹran Ileya fawọn alaini ni

Kayeefi ni ọrọ naa jẹ o. Ohun to si ṣe jẹ kayeefi ni pe pasitọ ni…

O ma ṣe o, Oloye Ayọ Fasanmi ti ku o

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkan pataki ninu awọn aṣaaju Yoruba, to tunjẹ ọkan ninu awọn olori ẹgbẹ…

Nitori bi wọn ko ṣe fun un ni tikẹẹti ni PDP, Agboola Ajayi fẹẹ dara pọ mọ ẹgbẹ ZLP

Igbakeji Gomina ipinlẹ Ondo, Agbọọla Ajayi, ti ko ọrọ rẹ to sọ lọsẹ to kọja pe…

O ma ṣe o, wọn ni Ọlabọde luyawo ẹ pa toyuntoyun l’Akurẹ

Awọn ọlọpaa ti mu ọkunrin kan ti wọn n pe ni Oluwaṣeun Ọlabọde o. Ẹsun pe…