Nitori gbese, Abiọdun fẹẹ bẹ sinu ọsa lọjọ ọdun, o ni ki omi kuku gbe oun lọ

Bi ko je awon ọlọpaa Eko ti won wa nitosi, eyi ti a n wi yii…

FA Cup: Arsenal gbo ewuro soju Chelsea

Ẹgbẹ agbabọọlu Arsenal ilẹ England ti fagba han alatako wọn, Chelsea, ninu aṣekagba FA Cup to…

Sanwo-Olu paṣẹ pe kawọn ileejọsin di ṣiṣi lati ọjọ keje, oṣu yii, l’Ekoo

Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Sanwo-Olu ti paṣẹ pe lati ọjọ keje, oṣu yii, ki awọn ileejọsin…

Awọn ọmọ iya meji ṣọdun Ileya latimọle, maaluu ni wọn ji gbe l’Ogbomọṣọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Bi gbogbo Musulumi kaakiri agbaye ṣe n dunnu, ti wọn yọ, lasiko ọdun…

Aṣọ ati ijẹkujẹ ni mo maa n fowo ti mo ba ri nidii ole jẹ – Andrew

Faith Adebọla, Eko Afi k’Ọlọrun maa ṣọ wa lọwọ awọn kọlọransi ẹda to kun igboro lasiko…

O ma ṣe o! Ọdun mejidinlogun lobinrin yii fi wa ọmọ, ọjọ kẹta to bi ibeji lo jade laye

 Bi ibanujẹ ba dapọ mọ ayọ, arojinlẹ lori iṣẹlẹ bẹẹ lo le jẹ keeyan maa dupẹ.…

Eeyan mẹfa ni Dosumu ti pa l’Ogere ati Ipẹru, ariwo oun fẹẹ mu ẹjẹ ni wọn lo n pa  

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Bi ẹ ṣe n ka iroyin yii, inu ibẹru ati ikayasoke lawọn eeyan…

Eyi lorukọ awọn ti yoo dije dupo gomina Ondo ti ajọ INEC fi sita

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ. Iyalẹnu nla lo jẹ fawọn eeyan ipinlẹ Ondo nigba ti wọn ri orukọ…

Onibaara lu alagbe ẹgbẹ ẹ pa l’Ekoo, o lo n yọju wo abẹ oun nigba toun n tọ

Faith Adebọla, Eko  Iyalẹnu gbaa niṣẹlẹ aburu kan to waye lagbegbe Victoria Island, l’Ekoo, yii jẹ…

Lẹyin ọjọ mọkanla, Fayẹmi bọ lọwọ Korona

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lẹyin ọjọ mọkanla ti Gomina Kayọde Fayẹmi tipinlẹ Ekiti ti ni arun Koronafairọọsi,…

Nitori  ibo Ondo to n bọ, Akeredolu ṣabẹwo si Tinubu

Ibo ti won yoo di ni ipinlẹ Ondo lati yan gomina tuntun ko ju oṣu meji…