Awọn ileewe ilẹ Yoruba yoo ṣi loṣu to n bọ

Oluyinka Soyemi Awọn ileewe to wa lawọn ipinlẹ mẹfẹẹfa nilẹ Yoruba yoo ṣi lọjọ kẹta, oṣu…

Magu kuro lahaamọ lẹyin ọjọ kẹwaa

Alaga ajọ to n gbogun ti ṣiṣe owo ilu basubaṣu tẹlẹ, Ibrahim Magu, ti kuro ninu…

Awọn alaga kansu ipinlẹ Ọyọ to pe Makinde lẹjọ fidi-rẹmi ni kootu

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ti Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti fi aṣẹ ijọba le…

Awọn eeyan ṣedaro Arotile, obinrin akọkọ to jagun pẹlu baaluu agberapa

Oluyinka Soyemi Lati ana, ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ti iroyin iku Tolulọpẹ Arotile ti gba igboro kan…

Aunti Sikira o le jawọ ninu arekereke, o ti di baraku

Awọn nnkan kan wa ti mo ti kọja, n ko si ni i gba ẹnikẹni laaye…

Ẹsun ikowojẹ pẹlu ole jija: Olori awọn EFCC wọ gau!

*Bẹẹ ki i ṣe pe Magu n lọ sewọn ree *Wọn fẹẹ fọrọ ẹ koba Tinubu…

Kọ́kọ́rọ́ ni pasitọ ni ki ọmọ ọdun mẹwaa kan lọọ mu wa ninu ile, lo ba fipa ba a lo pọ l’Ọdẹda

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọsẹ to kọja ni aṣiri Pasitọ Oyebọla to ba ọmọ bibi inu ẹ…

Wọn mu Moses pe o n ṣe ayederu oogun oyinbo l’Ọta

*Lo ba loun ko ti i jere kankan nibẹ Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ko jọ pe mimu…

Ko pẹ ti Tunde ati Tokunbọ tẹwọn de ni wọn tun lọọ jale l’Oshodi-Oke

Faith Adebọla, Eko Bi ọdọmọkunrin kan, Tunde Ọlaiya, ṣe maa n jade laaarọ, ti yoo wọle…

Awọn ọrẹ mẹta gbẹbọ n’Ikorodu, lawọn ọdọ adugbo ba ni ki wọn ko o jẹ

Faith Adebọla, Eko Adugbo kan ti wọn n pe ni Orita, ni Igbo Agbọwa, lagbegbe Ikorodu,…

Agbanah dẹ agbaana sawọn oyinbo Amẹrika, nile-ẹjọ ba sọ ọ sẹwọn oṣu mẹfa

Ọlawale Ajao, Ibadan Ọpọ oyinbo ara Amẹrika lo ti n ṣiṣẹ erin, ṣugbọn ti wọn n…