Lori owo awọn oṣiṣẹ-fẹyinti, PDP fẹsun jibiti kan Fayẹmi

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ oṣelu People’s Democratic Party nipinlẹ Ekiti ti fẹsun kan Gomina Kayọde Fayẹmi…

Eyi ni bi awọn agbebọn ṣe ji awọn eeyan gbe n’Isinbọde-Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ọjọ Ẹti, Furaidee, to kọja yii yoo jẹ manigbagbe fawọn eeyan ilu Isinbọde-Ekiti…

Wahala ẹgbẹ APC n le si i l’Ondo

*’Akeredolu ati alaga APC lo ni ka yọ Agboọla’ *Adajọ agba ni ko sohun to jọ…

Pasitọ fẹẹ kọ iyawo rẹ silẹ ni Ṣaki, lobinrin naa ba ni o ti fẹ ẹlomi-in ni

Olu-Theo Omolohun, Oke-Ogun Ibi tọrọ tọkọ-taya kan ti wọn jẹ ojiṣẹ Ọlọrun ti wọn fẹẹ pin…

Eyi ni bi wọn ṣe yinbọn pa Ẹbila, ọga awọn ‘One Million Boys’ n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin oṣu mẹta ti awọn ikọ ọmọ iṣọta ta a mọ si ‘One Million…

Kẹhinde ja purofẹsọ lole, o tun fipa ba agbalagba lo pọ

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Iwa ọdaju ti ọkunrin kan, Kẹhinde Oke, hu loṣu kejila, ọdun to kọja,…

Awọn ọmọ ẹgbẹ PDP binu si Agboọla, Igbakeji Gomina Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọpọlọpọ awọn ọmọ ẹgbẹ oṣelu PDP nipinlẹ Ondo ni wọn fẹhonu han tako…

2023: Ilẹ Yoruba ṣetan lati gbajọba, ọrọ ku sọwọ Tinubu, Fayẹmi – ARG

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ Afẹnifẹre Renewal Group (ARG) ti sọ pe ilẹ Yoruba ṣetan lati gba…

Magu, olori EFCC tẹlẹ, ti tun n kawọ sẹyin rojọ

Loni-in ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ kẹtala oṣu keje, ọdun 2020, Ọgbẹni Ibrahim Magu ti i ṣe…

Eeyan marundinlaaadọrin ko arun Korona lọjọ kan ṣoṣo nipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Lọjọ Abamẹta, Satide to kọja, nikan ṣoṣo, eeyan marundinlaaadọrin (65) lo ko arun Korona…

Awọn oluranlọwọ igbakeji gomina Kwara ti ko arun Korona

Stephen Ajagbe, Ilọrin Lẹyin ọjọ diẹ ti arun Korona pa olori oṣiṣẹ gomina nipinlẹ Kwara, Aminu Adisa…