Buhari yan Alkali bii adele ọga ọlọpaa tuntun

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Aarẹ Muhammadu Buhari ti yan igbakeji ọga ọlọpaa tẹlẹ, Alkali Usman Baba,…

Makinde ṣeleri iranwọ fawọn oniṣowo ti ina ba dukia wọn jẹ n’lsọ paati n’Ibadan

Ọlawale Ajao, Ibadan   Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti ṣeleri iranlọwọ fawọn ontaja ti…

Nitori ọrọ aabo, Sheikh Gumi ṣabẹwo s’Ọbasanjọ l’Abẹokuta

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Gbajugbaja Aafaa ilu Kaduna nni, Sheikh Ahmad Gumi, ti ṣabẹwo si aarẹ…

Aburo iyawo ẹ ni Jonas ki mọlẹ, lo ba ṣe e yankanyankan ni Festac

Faith Adebọla, Eko     Jonas Nnubia ni wọn porukọ baale ile ẹni ọdun mẹrinlelogoji yii,…

Òkèlè nla to nira lati gbe mi ni iku Yinka Odumakin – Ọọni

Florence Babaṣọla   Arole Oduduwa to tun jẹ Ọọni ti Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọjaja…

Gani Adams ni ki wọn gbe kọmiṣanna ọlọpaa Ọyọ kuro, o lobìnrin naa ko jafafa to

  Ki eto aabo le fẹsẹ rinlẹ daadaaa nipinlẹ Ọyọ, Aarẹ Ọnakakanfo ilẹ Yoruba, Iba Gani…

Apaayan ọmọ ẹgbẹ ‘Ẹiyẹ’ ni Ṣẹgun, ibi to ti n sa kiri lọwọ ti ba a n’Ikorodu Faith Adebọla, Eko

Faith Adebọla, Eko       Ti wọn ba n wa oṣikatan tẹsẹ mọrin ẹda, ọkunrin…

Oṣiṣẹ banki kowo awọn onibaara jẹ l’Abẹokuta, nile-ẹjọ ba sọ ọ sẹwọn oṣu kan aabọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Oṣiṣẹ banki kereje (Micro finance) ni Ọgbẹni Philips Ogorome, ẹni ọdun mọkanlelogoji…

A fura pe Yinka yoo ku – Jacob Odumakin

  Ọkan lara awọn ẹgbọn Oloogbe Yinka Odumakin, Pasitọ Jacob Odumakin, ti sọ pe asọtẹlẹ ti…

Eyi ni bawọn Fulani ṣe tun ya wọnu oko oloko n’Ibadan, eeyan mẹta ni wọn ji gbe

Ọlawale Ajao, Ibadan   O kere tan, eeyan mẹta lawọn Fulani ajinigbe tun ji gbe n’Ibadan…

Adigunjale ni Saidi, ibọn ibilẹ lo fi n da wọn laamu ni Festac

Faith Adebọla, Eko     Saidi Adewale lorukọ ọmọ ọdun mẹtadinlogoji yii, ọdọ awọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ…