Ẹ wo Pasitọ Shobọwale to fipa ba ọmọ ọdun mẹtadinlogun lo pọ n’Ifọ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Iwadii to lọọrin gidi ti bẹrẹ bayii lori ọkunrin yii, Pasitọ Tayọ Shobọwalẹ,…

Pasuma fọmọ rẹ f’ọkọ, o ni Ayọ̀ nla ni foun

Ọkan pataki ninu awọn ilu mo-ọn-ka onifuji ile wa nni, Àlàájì Alabi Pasuma ko le pa…

Marundinlaaadọrun ninu awọn ẹlẹwọn to sa lọ ni Imo ti pada sibẹ funra wọn

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta   Iroyin to tẹ ALAROYE lọwọ bayii ni pe marundinlaaadọrun ninu awọn ẹlẹwọn…

Awa o sọ pe a fẹẹ ṣatilẹyin fun Tinubu o-Ẹgbẹ Afẹnifẹre

Faith Adebọla Yatọ si iroyin kan to n ja ranyin lori atẹ ayelujara laipẹ yii, nibi…

Mọto ti wọn ni ki Kazeem fọ ni Festac lo n gbe sa lọ tọwọ fi ba a n’Idoroko

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta   Bi Kazeem Ọlanrewaju tẹ ẹ n wo yii ṣe n fi mọto sare,…

Ọkan lara awọn ọlọdẹ tawọn agbebọn yinbọn fun ni Ifẹwara ti ku o

  Florence Babaṣọla   Ọkan lara awọn ọlọdẹ ti wọn n ṣọ awọn oyinbo meji tawọn…

Eyi ni ọrọ idaro ti iyawo Yinka Odumakin kọ nipa ọkọ rẹ

  ”To ba jẹ ka mi sinu mi sita la n na bii owo laye, aa…

Mo mọ Tinubu daadaa, oun lo le ṣe aarẹ lọdun 2023- Alagba Faṣọranti

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta   Olori ẹgbẹ Afẹnifẹre to ṣẹṣẹ gbe kinni ọhun silẹ fun Oloye Ayọ Adebanjọ,…

Ọwọ tẹ awọn Fulani mẹta pẹlu nnkan ija oloro l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ   Ọwọ ileesẹ ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti tẹ awọn Fulani mẹta ti wọn…

Awọn agbebọn ji oyinbo meji gbe n’Ifẹwara

Florence Babaṣọla Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti sọ pe iwadii ti bẹrẹ lori iṣẹlẹ ijinigbe kan…

Ọrọ ijọba ibilẹ ni Naijiria nilo adura, ojoojumọ lo n buru si i fun wọn- Ọbasanjọ

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta   Lọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọjọ kẹfa, ọsu kẹrin, ọdun 2021 yii, Aarẹ fẹgbẹ awọn…