Stephen Ajagbe, Ilorin Afurasi kan, Muhammadu Mailemu, to n gbe laduugbo Banni, lagbegbe Sango, niluu…
Author: admin
Nitori ṣọja atawọn mi-in ti wọn ji gbe, awọn agbofinro ya lu igbo ọna Ibadan s’Ijẹbu-Ode
Ọlawale Ajao, Ibadan Ba a ṣe n wi yii, inu igbo ni ikọ oluwadii laarin…
Ọọni yan Toyin Kọlade ni Iyalaje Oodua
Florence Babaṣọla Ọọni Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, ti kede oludari apapọ ọdun Aje, Ọmọọbabinrin…
Awọn ajinigbe tun ji soja atawọn meji mi-in gbe n’Ibadan
Ọlawale Ajao, Ibadan Ọrọ awọn ajinigbe nipinlẹ Ọyọ bọna mi-in yọ lọsẹ yii pẹlu bi…
Ọpẹ o, wọn ti ri dokita ati nọọsi ti wọn ji gbe n’Imẹkọ gba pada
Adebiyi Adefunkẹ, Abẹokuta Dokita Ọladunni Ọdẹtọla ati Nọọsi Bamgboṣe tawọn ajinigbe ji l’Ọjọruu Wẹsidee, ọsẹ…
Wọn ba ageku ara Iya Ganiya Elekuru ninu ile babalawo n’Ileefẹ
Florence Babaṣọla Kayeefi lọrọ naa ṣi n jẹ fun awọn eeyan agbegbe Irẹmọ, niluu Ileefẹ, pẹlu…
Derrick fada ge ọwọ ọmọbinrin yii bọ nitori ko gba ko fipa ba a lo pọ
Ko si idi kan fun ọmọdebinrin yii, Evelyn Namasopo, ọmọ ọdun mẹrindinlogun (16)lati padanu ọwọ rẹ…
Ewurẹ mẹwaa lawọn ọrẹ meji yii lọọ ji gbe niluu igẹmọ-Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Iwadii ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ekiti ti bẹrẹ lori awọn afurasi meji kan tọwọ…
Awọn ajinigbe ji oniṣowo epo bẹntiroolu n’Iṣan-Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Lẹyin oṣu mẹta tawọn ajinigbe kan ji oloye ẹgbẹ awọn oniṣowo epo bẹntiroolu…
Nitori adigunjale tawọn ọdọ lu pa s’aduugbo wọn, baale ile mẹta dero ahamọ n’Ikọtun
Faith Adebọla, Eko Ahamọ awọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ lawọn baale ile mẹta kan ti…
Wọn ji dokita ati nọọsi gbe loju ọna Abẹokuta s’Imẹkọ
Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Dokita agba lọsibitu Jẹnẹra Imẹkọ-Afọn, Ọladunni Ọdẹtọla, ati nọọsi kan, Abilekọ Bamgboṣe, ti wa…