Iṣoro Naijiria kọja eyi ti Buhari le yanju, ki ẹnikẹni ma ro pe ayipada yoo wa ṣaaju 2023 – Biṣọọbu Adeoye

Alukooro igbimọ awọn Biṣọọbu lagbaaye (World Bishops Council) nilẹ Afrika, Biṣọọbu Ṣeun Adeoye, ti sọ pe iṣoro…

fidio: ÀWỌN ỌMỌ YORÙBÁ FI ÀÌDUNNÚ WỌN HÀN SÍ SUNDAY ÌGBÒHO TÍ WỌ́N MÚ

Fidio: AWỌN DSS TI MU SUNDAY IGBOHO NI KUTỌNU

Awọn DSS ti mu Sunday Igboho

Iroyin to n tẹ wa lọwọ ni pe ileeṣẹ DSS, iyẹn awọn ọtẹlẹmuyẹ, ti mu Oloye…

Ipo ti mo ba mọlẹbi ọmọbinrin ti wọn pa s’Ọjọta lasiko iwọde ‘Yoruba Nation’ ṣe mi laaanu lo jẹ ki n fun wọn lowo-Mr Macaroni

Faith Adebọla Gbajugbaja adẹrin-in poṣonu ilẹ wa nni, Ọgbẹni Debọ Adedayọ, tawọn eeyan mọ si Mista…

Bireeki tanka epo feeli, lo ba tẹ awọn ọmọleewe mẹẹẹdogun pa

Faith Adebọla Iran buruku ni iran ọhun, iran ti ko dun un wo rara, tori teeyan…

Ọmọ ẹgbẹ okunkun mẹta bọ sọwọ ọlọpaa n’Igbesa, wọn fipa fa ọkunrin kan wọnu ẹgbẹ wọn ni

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta          Ẹgbẹ okunkun kan wa ti wọn n pe ni  ‘Supreme Vikens Confraternity’.  Ẹgbẹ naa lawọn gende…

Nitori fiimu ‘Ọkọ Iyabọ, TAMPAN fofin de Yọmi Fabiyi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  TAMPAN, ẹgbẹ awọn onitiata, ranṣẹ pe Yọmi Fabiyi lati waa ṣalaye ara ẹ…

Nitori fiimu ‘Ọkọ Iyabọ, TAMPAN fofin de Yọmi Fabiyi

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta  TAMPAN, ẹgbẹ awọn onitiata, ranṣẹ pe Yọmi Fabiyi lati waa ṣalaye ara ẹ…

Awọn ti a mu nibi iwọde Yoruba Nation ree o – Ọga ọlọpaa Eko

Ọga ọlọpaa ipinlẹ Eko, Hakeem Odumosu, ṣe afihan awọn eeyan mọkandinlaadọta kan loni-in ọjọ aiku, Sannde,…

Awọn agbebọn ji pasitọ ijọ Deeper Life gbe ninu sọọsi rẹ l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Pasitọ ijọ Deeper Life kan, Ọtamayọmi Ogedemgbe, lawọn ajinigbe kan tun ji gbe…