Nitori ti wọn lu mọto onimọto ta ni gbanjo, ijọba ranṣẹ pe ọga FRSC ipinlẹ Ọyọ

Ọlawale Ajao, Ibadan   Igbimọ ti ijọba ipinlẹ Ọyọ gbe kalẹ lati ṣewadii iya to jẹ…

Ẹwọn n run nimu Raji, ọmọ ọdun mẹtala lo fun loyun ni Saki

Afaimọ ki ọkunrin ẹni ọdun mọkandinlaaadọta kan, Tairu Raheem, ma faṣọ penpe roko ọba lori ẹsun…

Afẹnifẹre gboṣuba nla fawọn OPC ti wọn mu Wakili Isikilu to n da awọn eeyan laamu n’Ibarapa

Ẹgbẹ Afẹnifẹre ti fidimule wọn han si bi ọwọ ṣe tẹ ọga awọn Fulani, Isikilu Wakilu,…

Ada yanran-yanran ni wọn ba lọwọ Joshua atawọn ọrẹ ẹ ti wọn jọ n ṣẹgbẹ okunkun l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko           Akolo awọn ọlọpaa ọtẹmuyẹ to wa ni Panti,…

Ọpẹ o, wọn ti ri awọn arinrinajo tawọn ajinigbe ji gbe loju-ọna Oṣogbo si Ibokun

Florence Babaṣọla   Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọṣun ti kede pe eeyan meje tawọn ajinigbe ji lalẹ…

Ọwọ ẹsọ Amọtẹkun tẹ awọn ọkunrin meji ti wọn n ṣe ‘kinni’ funra wọn l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ       Boroboro bii ajẹ to jẹ eepo ọbọ ni awọn ọkunrin…

Ibi ti Ambọde n tukọ ipinlẹ Eko lọ ko dara la ko ṣe ṣatilẹyin fun saa keji rẹ – Tinubu

Faith Adebọla, Eko       Aṣaaju apapọ fẹgbẹ oṣelu All People’s Congress, APC, to tun…

Aisun ọdun tuntun lemi ati baba mi ti n bọ tawọn ọlọpaa fi yinbọn pa wọn n’Iwoo – Oluṣẹgun

Florence Babaṣọla       Oluṣẹgun Ọlaoṣebikan fara han niwaju igbimọ tijọba ipinlẹ Ọṣun gbe kalẹ…

Akeredolu pasẹ pe kawọn ileewe maa kọrin ibilẹ Yoruba

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ       Gomina Rotimi Akeredolu ti ni o di dandan fun gbogbo…

Awọn ọmọ ẹgbẹ PDP fẹhonu han l’ Ọyọọ, wọn ni wọn fi tipa yan oludije le awọn lori

Ọlawale Ajao, Ibadan     O fi han pe nnkan ko lọ deede ninu ẹgbẹ oṣelu…

Awọn agbebọn pa Samson l’Akungba Akoko, wọn tun ji ọkada rẹ lọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ.   Awọn ọlọpaa ti bẹrẹ iwadii lori iṣẹlẹ iku ọlọkada kan, Samson Owodayọ,…