Wọn wole ijọba ipinlẹ Ọyọ to wa l’Abuja

Ọlawale Ajao, Ibadan     Bi eeyan ba dé ibi ti ile ijọba ipinlẹ Ọyọ to…

Ọwọ EFCC ba awọn ọmọ ‘Yahoo’ mẹtala ni Lẹkki

Faith Adebọla, Eko       Agbegbe Lẹkki lawọn mẹtala to wa ninu fọto yii sa…

Aja to bu ọga ọlọpaa jẹ atolowo ẹ dero ahamọ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Afaimọ ki baba agbalagba kan, Abayọmi Adeyẹmi, ati Aja rẹ latari bi wọn…

Ilé-ẹjọ́ ni ki awọn to pa Agboọla kọkọ lọọ gbatẹgun ọsẹ mejila lọgba ẹwọn

Ọlawale Ajao, Ibadan Awọn afurasi apaayan tó ràn àgbẹ aladaa-nla nni, Ọgbẹni Oluwọle Agboọla, lọ sọrun…

Ijọba Kwara pin miliọnu mọkanlelọgbọn fawọn to fara gba ninu ijamba epo bẹntiroolu ni Jẹbba

Stephen Ajagbe, ilorin Ijọba ipinlẹ Kwara, l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, bẹrẹ pinpin miliọnu mọkanlelọgbọn naira to…

Nitori ija ilu Ẹrinle ati Ọffa, gomina Kwara kede konilegbele

Stephen Ajagbe, Ilorin Nitori ija mi-in to tun bẹ silẹ l’Ọjọbọ, Tọsidee, ọsẹ yii, laarin awọn…

Wọn paayan meji, wọn ṣe ọpọ agbofinro leṣe ninu ija Fúlàní ati Yorùbá ni ipinlẹ Ọyọ

Eeyan meji ku, wọn ṣe ẹṣọ Amọtẹkun leṣe nibi ija Fulani ati Yoruba l’Ọyọọ Ọlawale Ajao,…

Awọn to dana sun ọja Ṣáṣá, n’Ibadan, ti dero ọgba ẹwọn Abolongo

Ọlawale Ajao, Ibadan Ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Ọyọ ti gbe meje ninu awọn afurasi ọdaran ti wọn…

Pasitọ to fipa bọmọ ọdun mẹrinla sun l’Ekoo ta ṣọọṣi ẹ, lo ba salọ

Faith Adebọla, Eko Oriṣiiriṣii ẹsun ati ẹri ni wọn ko kalẹ nile-ẹjọ l’Ọjọbọ, Tọsidee yii, latari…

Ileewe awọn ọlọpaa ni Babangida atawọn ẹgbẹ ẹ ti lọọ jale

Faith Adebọla, Eko Pako bii maaluu to r’ọbẹ lọwọ alapata lawọn afurasi ọdaran mẹrin kan n…

Ọga agba Poli Ado-Ekiti pariwo: Irọ ni wọn n pa, emi o ṣe owo ileewe baṣubaṣu o

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Wahala nla lo bẹrẹ lọjọ Aje, Mọnde to kọja, nileewe poli ijọba apapọ,…