Ẹ ẹ ri i pe iṣẹ Ọlọrun yii ko ṣee tu wo, Ọba alaṣepe ni

Gbogbo ọna ni ọkan mi fi balẹ, nitori awọn iṣẹ ti kaluku n jẹ fun mi…

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Fayẹmi l’Ekiti pẹlu awọn ọrẹ rẹ Nigba miiran, awọn oloṣelu fẹran ẹtan, wọn yoo si maa…

O ṣoju mi koro (Apa Kin-in-ni)

Kin ni ijọba Buhari yii fẹ gan-an? Ijọba Naijiria gbe ofin tuntun kan jade, ofin to…

Fidio: Olori ẹgbẹ Asọludẹrọ to mu Sunday, apaayan Akinyẹle, ti ṣalaye bi wọn ṣe mu un fun ALAROYE

Ọlawale Ajao, Ibadan  

Ideye darapọ mọ Goztepe ilẹ Turkey

Oluyinka Soyemi Agbabọọlu ilẹ Naijiria, Brown Ideye, ti darapọ mọ ẹgbẹ agbabọọlu Goztepe ilẹ Turkey. Gẹgẹ…

Korona tun pa elomi-in l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ijọba ipinlẹ Ekiti ti kede pe arun Koronafairọọsi ti pa ẹni kan nipinlẹ naa…

Fidio: Ọkan ninu awọn baalẹ Akinyẹle, nibi ti Sunday ti n ṣa awọn eeyan pa, ti b’ALAROYE sọrọ

Nitori ipolongo to ṣe fun Fayẹmi, awọn aṣofin fun alaga ijọba ibilẹ Ikẹrẹ niwee gbele-ẹ

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ile-igbimọ aṣofin ipinlẹ Ekiti ti fun alaga ijọba ibilẹ Ikẹrẹ, Ọnarebu Fẹmi Ayọdele,…

Eyi ni bawọn aṣaaju Hausa-Fulani ṣe ba Naijiria yii jẹ (13)

Gẹgẹ bii ileri ti mo ṣe lori ọrọ ti a n ba bọ latẹyin, mo sọ…

Nibo lẹyin n gbe, nibo lẹyin wa: Nigba t’Abiọla atawọn eeyan rẹ kọju ija si Awolọwọ ni 1979 (7)

*Idi abajọ ree o Bo ba ṣe pe ko si nnkan kan nibẹ tẹlẹ, ti wọn…

O ṣoju mi koro (Apa Keji)

Isiaka Akintọla, ori ọkẹrẹ koko lawo, ba a wi fọmọ ẹni a gbọ Nigba ti bata…