Monisọla Saka Abilekọ kan ati ọmọ ẹ obinrin ọmọ ọdun mẹjọ, ni wọn ti ṣe bẹẹ…
Author: admin
Ori aatan lawọn fijilante ti ri ọmọ tuntun kan he loru
Monisọla Saka Awọn ọdẹ agbegbe Díòbú, Port Harcourt, nipinlẹ Rivers, to n ṣọ adugbo, ti wọn…
Wọn ti mu Hashimu, ọmọ ọdun mẹrin lo fipa ba lo pọ
Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ aabo ara ẹni laabo ilu, Nigeria Security and Civil Defence Corps (NCSDC),…
Eeyan mẹrindinlogun jona ku ninu ijamba ọkọ l’Ọdẹ-Omu
Florence Babaṣọla, Osogbo O kere tan, eeyan mẹrindinlogun lo jona kọja idanimọ, nigba ti awọn mọto…
Ijamba ina ṣẹlẹ laafin Ọọni, ọpọ dukia lo ṣofo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Akọwe iroyin fun Ọọni Ifẹ, Ọba Adeyẹye Ẹnitan Ogunwusi, Ọtunba Moses Ọlafare, ti…
Ijọba ti sun ọjọ eto ikaniyan to yẹ ko waye siwaju
Adewale Adeoye Ni bayii, awọn alaṣẹ ijọba orileede yii ti sọ pe awọn ti dawọ eto…
Ọnarebu to fipa ba aburo iyawo rẹ lo pọ ti ha sọwọ ọlọpaa
Adewale Adeoye Kọmiṣanna ọlọpaa nipinlẹ Cross Rivers, Balarabe Sule, ti sọ pe ọdọ awọn ni Ọnarebu…
Ọkunrin yii daju o, o ka’yawo ẹ mọ abẹ ale, lo ba ṣa awọn mejeeji ladaa pa
Monisọla Saka Joly Tyang, ọkunrin ọmọ orilẹ-ede Cameroon kan, ti lọọ fa ara ẹ le awọn…
Nitori iyawo ile to fẹẹ ṣe baṣubaṣu, kọmiṣanna yọ DPO nipo
Monisọla Saka Kọmiṣanna ọlọpaa nipinlẹ Eko, CP Idowu Owohunwa, ti paṣẹ pe ki wọn yọ DPO, ẹka…
Lẹyin ọdun mẹsan-an lakata Boko Haram, akẹkọọ-binrin ileewe Chibok meji jajabọ
Faith Adebọla Meji ninu awọn akẹkọọ-binrin rẹpẹtẹ ti ileewe Government Secondary School, to wa niluu Chibok,…
Ọmọdekunrin yii ja bọ sinu odo nla nibi to ti n ṣa ike kiri
Faith Adebọla, Eko Iku ti ti iba paayan, to ba ṣi ni fila, keeyan dupẹ lọwọ…