Adewale Adeoye Awọn agba bọ wọn ni, beeyan ba dakẹ, tara rẹ, a baa dakẹ ni,…
Author: admin
Wọn ti dajọ iku fun pasitọ ijọ to pa ọmọ ẹgbẹ akọrin ṣọọṣi rẹ to fun loyun
Adewale Adeoye Iku ni ere ẹṣẹ gẹgẹ bi ọn ṣe maa n sọ, ere agbere ati…
Ọwọ tẹ ole ajifoonu to mura bii alaamojuto idanwo ni Fasiti Ifẹ
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ahesọ to kọkọ n lọ kaakiri ni pe alaamojuto idanwo (Invigilator) ni ọkunrin…
O ma ṣe o, ọfọ nla ṣẹ Saidi Balogun
Jọkẹ Amọri Inu ibanujẹ nla ni oṣere ilẹ wa to ti tun mu oṣelu mọ iṣẹ…
Nitori owo iranwọ ori epo ti wọn yọ, gomina yii ṣafikun owo-oṣu awọn oṣiṣẹ
Monisọla Saka Lati mu ki irọrun de ba awọn araalu, paapaa ju lọ awọn oṣiṣẹ ijọba,…
Aarẹ Tinubu ko lẹtọọ lati yan olori le awọn aṣofin lọwọ -Ẹgbẹ agba Hausa
Adewale Adeoye Ẹgbẹ agba ẹya Hausa kan ti wọn n pe ni ‘Northern Elders Forum’ (NEF)…
Ẹgbẹ ọmọ Ekiti kilọ fun Fayẹmi: Da ogun biliọnu owo ilu to o ko jẹ pada
Monisọla Saka Ẹgbẹ awọn ọmọ bibi ilu Ekiti kan, Ekiti Patriotic Consultative Forum (EPCF), ti gba…
Oṣere tiata tun bimọ fun Portable olorin zah zuu
Monisọla Saka Ọkunrin olorin hip hop tawọn ọdọ isinyii n ko jẹ nigboro, Habeeb Okikiọla ọmọ…
O ma ṣe o, akẹkọọ fasiti yii ku lẹyin to pari idanwo aṣekagba rẹ
Adewale Adeoye Titi di akoko ta a n ko iroyin yii jọ, inu ọfọ nla gbaa…
Awọn ṣọja ṣawari ileeṣẹ ti wọn ti n ta ọmọ tuntun, ọpọlọpọ aboyun ni wọn ko kuro nibẹ
Monisọla Saka Ọwọ palaba awọn amookunṣika ẹda ti ṣegi pẹlu bi awọn ọmọ ogun ilẹ Naijiria,…
Adajọ ju Ariyibi sẹwọn ọdun marun-un, kokeeni lo gbe
Adewale Adeoye Ni bayii, adajọ ile-ẹjọ giga kan niluu Eko, Onidaajọ Chukwuejekwu Aneke, ti ni ki…