Awọn oṣiṣẹ kootu naa lawọn maa daṣẹ silẹ o

Adewale Adeoye A n pe ọrọ ọhun lọwẹ, o n laro ninu o, bii ere, bii…

Bi Tinubu ba pe mi lati ba a ṣisẹ, ma a kọkọ gba iyọnda lọwọ awọn eeyan wọnyi-Wike

Adewale Adeoye Gomina ipinlẹ Rivers tẹlẹ, Ọgbẹni Nysom Wike, ti sọ pe ki i ṣe pe…

Nitori ọrọ owo iranwọ epo bẹntiroolu, Falana ṣabẹwo si Tinubu

Monisọla Saka Lọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹta, oṣu Kẹfa, ọdun yii, ni agba agbẹjọro nilẹ wa…

Ijọ Katoliiki Ondo ṣeranti ọdun kan tawọn agbebọn waa paayan rẹpẹtẹ nibẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọjọ Aje, Mọnde, ọjọ karun-un, oṣu Kẹfa, ọdun 2023 yii, ni gbogbo ọmọ…

Igbẹjọ ko-tẹmi-lọrun: Tọọgi APC ya bo kootu, wọn fẹgba le awọn PDP jade

Gbenga Amos Ẹkọ ko ṣọju mimu nibi ijokoo kootu to n gbọ ẹsun to su yọ…

Ọmọlayọ ti dero ẹwọn, tiṣa loun atawọn ẹgbẹ ẹ lu lalubami

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ile-ẹjọ Majisireeti to fikalẹ siluu Odigbo, ti ni ki akẹkọọ kan ti ko…

Nitori ẹjọ ti adajọ da fun un, Akala fo windo jade ni kootu, lo ba fere ge e

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ṣe lọrọ ọhun da bii ere ori-itage, nigba ti ọkunrin afurasi kan ti…

Ẹgbẹ oṣiṣẹ ileeṣẹ mọnamọna lawọn yoo darapọ mọ NLC fun iyanṣẹlodi ti wọn fẹẹ ṣe

Monisọla Saka Awọn oṣiṣẹ ileeṣẹ mọnamọna jake-jado orilẹ-ede Naijiria, labẹ ẹgbẹ wọn ti wọn n pe…

Ẹgbẹ onimọto Ọyọ: Makinde yan Ọmọlẹwa, Tokyo, Ejiogbe rọpo Auxiliary

Ọlawale Ajao, Ibadan Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ẹnjinnia Ṣeyi Makinde, ti yan awọn eeyan tuntun sinu igbimọ…

Adajọ ni ki wọn lọọ yẹgi fawọn obinrin mẹta ti wọn jẹbi ẹsun ijinigbe

Faith Adebọla  Boya owe awọn agba ti wọn ni ọdẹ ki i pa ọdẹ jaye, ko…

Ile-ẹjọ maa gba ẹtọ mi pada fun mi lọwọ ijọba awuruju yii-Atiku

Adewale Adeoye Ondije dupo aarẹ orileede yii lẹgbẹ oṣelu ẹgbẹ PDP ninu ibo aarẹ to waye…