Baba agbalagba yii fipa b’ọmọọdun mẹsan-an lo pọ, o l’ọmọ naa ṣẹju soun ni

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa kan lagbegbe Gangaraso, nijọba ibilẹ Jada, nipinlẹ Adamawa, ti sọ pe ọdọ…

Ẹ wo Taiwo, awọn oni POS lo n lu ni jibiti n’Ilọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọwọ ti tẹ ogbologboo ole kan, Akinrotimi Taiwo, to n ja awọn oni…

Wahala n bọ o, nitori Tinubu, ẹgbẹ oṣo at’ajẹ pẹlu awọn pasitọ fẹẹ kọju ija sira wọn

Monisọla Saka Afaimọ ki ija nla ma waye laarin awọn ẹgbẹ oṣo ati ajẹ lorileede yii…

Nibi to ti n sare buruku, ọkọ akẹru wo pa alabaaru l’Ekoo

Monisọla Saka Ọkunrin Mọla to n fi ọmọlanke titi ṣiṣẹ ṣe ti pada iku ojiji lọsan-an…

Eyi nidi ti wọn ko ṣe fun mi lami-ẹyẹ nibi eto AMVCA- Ibrahim Chatta

Adewale Adeoye Gbajumọ oṣere tiata nni, Ibrahim Chatta, ti sọ pe ki i ṣe tuntun rara…

Mo ti dariji Tinubu o- Bode George

Adewale Adeoye Alagba Bode George, to ti figba kan jẹ igbakeji alaga ẹgbẹ oṣelu PDP nilẹ…

Mi o ni i pe Tinubu ni ‘aarẹ mi’ laelae- Pasitọ Tunde Bakare

Adewale Adeoye Oludasilẹ ati oluṣọagutan agba ṣọọṣi kan ti wọn n pe ni, ‘Citadel Global Community…

Amunibuni ni Sunday yii, ọmọ pasitọ to n digunjale

Adewale Adeoye Ileeṣẹ ọlọpaa agbegbe Warri, nipinlẹ Delta, ti sọ pe, ọwọ awọn ti tẹ Ọgbẹni…

Oṣere yii ti bẹbẹ o: Funkẹ Akindele, jọwọ, dariji mi, ọmọde lo ṣe mi

Monisọla Saka Ọkan lara awọn oṣerebinrin ilẹ wa, Juliana Ọlayọde, to gbajumọ ninu ipa Toyọsi tabi…

Wan ṣanṣi lawọn mẹrin yii n ṣe, ero ti wọn ba gbe ni wọn n ja lole

Adewale Adeoye Awọn ọlọpaa agbegbe Asaba, nipinlẹ Delta, ti mu mẹrin lara awọn ọdaran kan ti…

Mi o tiẹ mọ ohun to rọ lu mi ti mo fi ba ọmọ mi laṣepọ – Adeyẹmi

Faith Adebọla Baale ile ẹni odun mejidinlọgbọn kan, Babatunde Adeyẹmi, ti ni kawọn ọlọpaa ṣe oun…