Adewale Adeoye Gende mẹtadinlogun lara awọn ọdaran to n ṣowo egboogi oloro laarin ilu Abẹokuta, nipinlẹ Ogun, lọwọ ajọ…
Author: admin
Inu ṣalanga ileewe ni Ibrahim ti lọọ fipa ba ọmọọdun meje lo pọ
Adewale Adeoye Ni bayii, awọn ọlọpaa agbegbe Itas Gadau, nijọba ibilẹ Itas Gadau, nipinlẹ Bauchi, ti sọ…
Wọn fẹẹ gba mi ni mi o ṣe lọ sibi ayẹyẹ igbaradi ibura Tinubu-Portable
Monisọla Saka Gẹgẹ bi aarẹ tuntun ti wọn ṣẹṣẹ dibo yan lorilẹ-ede yii, Aṣiwaju Bọla Ahmed…
Aarẹ Buhari mu Tinubu yika inu Aso Rock, l’Abuja
Adewale Adeoye Leyin ti won kirun Jimọ tan lọjọ Eti, Furaidee, ọjọ Kẹrindinlọgbọn, oṣu Karun-un, ọdun…
Kootu da ẹjọ ti wọn pe ta ko Tinubu nu, wọn tun paṣẹ kawọn olupẹjọ sanwo itanran
Monisọla Saka Lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹrindinlọgbọn, oṣu Karun-un, ọdun yii, ni ile-ẹjọ giga kan niluu…
Mo kọwe sileeṣẹ ọlọpaa pe mi o ṣiṣẹ mọ, wọn o jẹ ki n lọ, iya ni wọn fi n jẹ mi – Fauzziyah
Adewale Adeoye Ọkan lara awọn ọlọpaa nipinlẹ Eko, Kọpura Fauzziyah Ebunọla Isiak ti fẹsun iwa ọdaran…
Tusidee to n bọ nidajọ yoo waye lori ku Timothy Adegoke
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, to n bọ, iyẹn ọgbọnjọ, oṣu Karun-un, ọdun yii, nidajọ…
Awon aṣofin Ọyọ tun yọ alaga kansu mi-in nipo
Ọlawale Ajao, Ibadan Laarin ọsẹ meji ti wọn da alaga ijọba ibilẹ Irẹpọ, Ọnarebu Sulaimon Lateef Adeniran, duro, ileegbimọ…
Abikẹ Dabiri binu si ileeṣẹ tẹlifiṣan Arise
Monisọla Saka Olori ileeṣẹ ijọba to n ri si ọrọ awọn ọmọ Naijiria to wa lẹyin…
Dẹrẹba at’ọmọọṣẹ rẹ ku sinu ijamba ọkọ
Ismail Adeẹyọ Awakọ kan, ati ọmọọṣẹ rẹ, tẹnikẹni ko tii mọ orukọ wọn lasiko ta a…