Eeyan kan ku, awọn mẹta fara pa, nibi ija Hausa ati Yoruba niluu Oṣogbo

 Florence Babaṣọla Eeyan kan lo ti ku bayii, nigba ti awọn mẹta mi-in fara pa nibi…

Francis ati Emmanuel gbe ọkada ọga wọn sa lọ l’Ekoo, Ogbere lọwọ ti tẹ wọn

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Ileeṣẹ kan to maa n fi ẹru ranṣẹ sawọn to ba ni in ni…

Wọn fabuku kan Pasitọ Tunde Bakare, “Pastor Ṣakabula” ni wọn n pe e bayii o

Ohun to ṣẹlẹ si Pasitọ Tunde Bakare, olori ijọ Latter Rain, lati ibẹrẹ ọsẹ yii, ko…

Lasiko ọdun Keresi, Buhari ṣeleri igba daadaa fawọn ọmọ Naijiria

Faith Adebọla Aarẹ orileede yii, Muhammadu Buhari ti bẹ gbogbo ọmọ orileede yii lati ma ṣe…

Isin aisun ọdun tuntun ko gbọdọ kọja aago mẹwaa alẹ l’Ekoo- Sanwo-Olu

Faith Adebọla, Eko  Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Oluṣọla Sanwo-Olu ti sọ pe loootọ nijọba ipinlẹ Eko…

Ọwọ tẹ awọn akẹkọọ ileewe Akọka, ọbẹ ni wọn fi n gba mọto lọwọ awọn eeyan

Faith Adebọla, Eko  Ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn gende meji ti wọn pe ara wọn lọmọleewe…

Ara gomina Eko ti ya patapata, wọn ni Koro ti kuro lara ẹ

Jide Alabi Lẹyin ọjọ mẹrinla to ti wa nibi ti wọn ti n tọju ẹ, nitori…

‘Diẹ lo ku ki awọn Amọtẹkun fibọn fọ mi lori n’Ibadan’

Ọlawale Ajao, Ibadan Bi ọrọ ti ayaworan kan n’Ibadan atawọn eeyan kan nigboro ilu naa sọ ba…

Ọgba ẹwọn ni Ahmed yoo ti sọdun tuntun o, ọmọ lanlọọdu ẹ lo ba lo pọ n’ Ilọrin 

Stephen Ajagbe, Ilọrin Olukọ ileewe ijọba kan, Ahmed Yusuf, tọwọ tẹ laipẹ yii pe o n…

Miliọnu lọna ogun naira lawọn ajinigbe to ji aburo aṣofin ipinlẹ Ọyọ gbe n beere fun

Ọlawale Ajao, Ibadan Ipenija eto aabo ti ipinlẹ Ọyọ n koju lọwọlọwọ yii tun ti gbọna…

Wọn sọ opopona kan lorukọ Anthony Joshua ni Ṣagamu

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Bi ọmọ ẹni ba daa ka wi, ki i ṣe ka le baa fi…