Lasiko iṣọ oru lawọn Fulani ya bo wọn ni ṣọọṣi CAC Waasinmi, wọn ja wọn lole, wọn tun ji ẹni kan gbe lọ

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Awọn ara ṣọọṣi CAC to wa ni Gudugbẹ Alagbọn, ni Waasinmi, nijọba ibilẹ Ewekoro,…

Boko Haram lọọ ka awọn agbẹ mọ’nu oko irẹsi ni Borno, ni wọn ba bẹ mẹrinlelogoji lori ninu wọn

Ni nnkan bii aago mọkanla aarọ ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kejidinlọgbọn, oṣu yii, ni wọn ni…

Ọọni Ifẹ bẹrẹ ayẹyẹ ọdun marun-un to gori itẹ, Alaafin ṣeleri atilẹyin fun un lori iṣọkan Yoruba

Dada Ajikanje Niṣe ni oriire n yi lu ara wọn fun Ọọnirisa, Ọba Enitan Ogunwusi, pẹlu…

Ọkunrin meji n ja sọmọ Topẹ Alabi, ṣugbọn ọmọ naa ni oun mọ baba oun

Jide Alabi Asiko yii ki i ṣe eyi to dara rara fun ọkan ninu awọn akọrin…

Eeyan mẹfa ku ninu ijamba ọkọ l’Ogere

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Ko din leeyan mẹfa to padanu ẹmi wọn ni nnkan bii aago meje…

L’Ọṣun, mọto ati ọkada fori sọ ara wọn, eeyan meji lo ku loju ẹsẹ

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Eeyan meji lo jẹ Ọlọrun nipe laaarọ ọjọ Abamẹta, Satide, nibi ijamba ọkọ…

O ma ṣe, awọn agbebọn yinbọn pa oluṣọ-aguntan kan l’Ekiti

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Awọn agbebọn kan ti wọn fura si gẹgẹ bii ajinigbe ti yinbọn pa…

Awọn ajinigbe ti yọnda iyawo olori awọn oṣiṣẹ gomina Ondo ti wọn ji gbe

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akure Iyawo olori awọn oṣiṣẹ lọfiisi gomina ipinlẹ Ondo ti wọn ji gbe lalẹ…

Ẹgbẹrun kan naira la ta ori awọn ọlọpaa mejeeji ta a gbe lọjọsi, aafaa kan n’Ilọrin lo fẹẹ fi wọn ṣoogun owo – Awọn afurasi ọdaran

Ọlawale Ajao, Ibadan Lẹyin ọsẹ mẹrin ti awọn ọmọ iṣọta ti dana sun ọlọpaa meji laduugbo…

Wọn ti sinku Babatunde, akẹkọọ UNIOSUN to binu pa ara ẹ

Florence Babaṣọla Ninu ẹkun, ibanujẹ ati aro ni wọn sinku Juba Babatunde Philips, akẹkọọ ileewe UNIOSUN…

Wọn ti ju Oluṣọla Alọ sẹwọn gbere l’Akure, ọmọ ẹ lo fipa ba lo pọ

Jide Alabi Ile-ẹjọ gíga kan niluu Àkúrẹ́ ti ni ki wọn lọọ ju ọkunrin kan, Alọ…