Daniel ja mọto gba l’Ekoo, Ogere lọwọ ti ba a

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta                              Mẹrin lawọn ikọ adigunjale  to gba mọto ayọkẹlẹ Camry ti nọmba ẹ jẹ AAA 212…

Ile-ẹjọ da Abubakar pada satimọle, ọkada lo ji ni Ṣaki

Olu-Theo Omolohun Oke-Ogun Latari bi afurasi ọdaran kan, Abubakar Bello, ṣe ni oun ko jẹbi ẹsun…

Ọga ọlọpaa kilọ fawọn ọlọkada l’Ọyọọ: Ẹni to ba tun kọ lu ọlọpaa yoo gba pe oun ṣi aye wa

Ọlawale Ajao, Ibadan “Ọlọkada to ba tun dana sun agọ ọlọpaa tabi kọ lu agbofinro yoo…

Awọn ajinigbe mẹta gba idajọ iku l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Adajọ Ile-ẹjọ giga to wa l’Akurẹ ti ni ki wọn lọọ yẹgi fawọn…

Ọlọpaa wa ibuba awọn ọmọ ẹgbẹ okunkun kan n’Ikorodu, ọwọ tẹ meje ninu wọn

Faith Adebọla, Eko Awari ti wọn lobinrin n wa nnkan ọbẹ lawọn ọlọpaa ọtẹlẹmuyẹ fi wiwa…

Wọn ka Kamọru mọ’bi to ti n fipa ṣe ‘kinni’ fọmọ ọdun mẹwaa l’Akurẹ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Diẹ lo ku ki wọn lu baba agbalagba kan pa nigba ti wọn…

Ijọba kilọ faraalu ni Kwara, nitori arun korona to tun pa eeyan kan

Stephen Ajagbe, Ilorin Ijọba Kwara ti ṣekilọ fawọn araalu lati maa kiyesara, ki wọn si tẹsiwaju…

Ẹẹmeji ọtọọtọ ni Ọlọrun fi han mi pe mo maa di gomina ipinlẹ Ọṣun- Oyetọla

Florence Babasola, Oṣogbo Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti sọ pe imọtẹlẹ Ọlọrun ni bi…

Johnson kọ iyawo ẹ n’Ibadan, o ni pasitọ ati alagba ijọ n ba a laṣepọ

Ọlawale Ajao, Ibadan Agbere ṣiṣe ti da idile Onigbagbọ ru n’Ibadan, ọkọ iyawo, Johson Olumuyiwa, fẹsun…

Awọn tijọba wo’le wọn ni Fagba n binu, wọn ni iwa ailaaanu nijọba hu

Faith Adebọla, Eko “Ṣe gbogbo awọn to ni ṣọọbu nibi lo n ta igbo tabi ọti…

 Awọn eeyan Agọ-Iwoye n binu si Dapọ Abiọdun, wọn lo gbẹsẹ le atunṣe ọna Igan

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Titi ta a fi pari iroyin yii ni ọpọ eeyan niluu Agọ-Iwoye ṣi…