Ibrahim Alagunmu O kere tan, eeyan mẹta lo ti rọrun alakeji, nigba ti ọpọlọpọ fara pa…
Category: Ìròyìn
Wọn ba ori ati ọwọ eeyan lọwọ Ibrahim ati Wasiu ni Kwara, oogun owo ni wọn fẹẹ fi i ṣe
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Akolo ọlọpaa lawọn ọkunrin meji yii, Wasiu Omonose, ẹni ọdun marundinlogoji, ati ẹnikeji…
Ijọba ipinlẹ Eko ṣi ileewe Chrisland pada
Monisola Saka Ijọba ipinlẹ Eko, latọwọ ileeṣẹ to n ri si eto ẹkọ n’ipinlẹ Eko, ti…
Adanu nla ni iku Alaafin jẹ fun iran Yoruba – Oluwoo
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Oluwoo ti ilu Iwo, Ọba Abdulrasheed Adewale Akanbi, ti ṣapejuwe iku Alaafin ti…
Ori ko awọn arinrin-ajo mẹsan-an yọ lọwọ awọn ajinigbe l’Ọrẹ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Awọn arinrin-ajo bii mẹsan-an lori ko yọ lọwọ awọn ajinigbe loju ọna marosẹ…
Ẹ wo Samuel atawọn ikọ rẹ ti wọn n digunjale l’Ọwọ
Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọlọpaa ipinlẹ Ondo ti fi pampẹ ofin gbe awọn ikọ adigunjale ẹlẹni mẹta…
Nitori isinku Alaafin, isede wa niluu Ọyọ lati aago mẹjọ alẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan Lati ṣe gbogbo etutu to yẹ lori iku ọba nla to waja nilẹ…
Aago mẹrin irọlẹ ni Ọba Adeyẹmi yoo wọ kaa ilẹ lọ
Ọlawale Ajao, Ibadan Aago mẹrin, nirọlẹ ọjọ Abamẹta, Satide yii, ni wọn yoo sinku Ọba Adeyẹmi…
Kayeefi nla, Owolabi ni ile aye su oun, lo ba fẹẹ pokunso ni Kwara
Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Ẹti, Furaide, opin ọsẹ to lọ yii, ni Arakunrin kan, Ọlayinka Ṣẹgun…
Erin wo! Alaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, ti waja
Ọlawale Ajao, Ibadan Alaafin Ọyọ, Ọba Lamidi Ọlayiwọla Adeyẹmi, ti darapọ mọ awọn baba nla rẹ…
Aisha Buhari fiwe pe awọn oludije dupo aarẹ, o ni ki wọn ma mu foonu wọn dani wa
Mosunmọla Saka Gbogbo awọn oludije dupo aarẹ kaakiri awọn ẹgbẹ oṣelu nilẹ Naijiria ni wọn yoo…