Awọn aṣofin Ogun ni ki EFCC waa tọpinpin Odusolu, ọga OPIC tẹlẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ileegbimọ aṣofin Ogun kede lọjọ Ẹti, Furaidee, ọjọ kẹtadinlogun, oṣu kẹsan-an yii, pe…

Nitori iṣọkan Naijiria ni mo ṣe darapọ mọ ẹgbẹ oṣelu APC-Fani-Kayọde

Faith Adebọla Bi ko ba nidii, obinrin ki i jẹ Kumolu, Oloye Fẹmi Fani-Kayọde sọ pe…

Ọjọ keje lẹyin ti ọkunrin yii gbaṣẹ onibiliọnu mọkandinlaaadọrin lo sun ti ko ji mọ

Iku ti i wọle adun ti i sọ ọ di kikan lo wọle idile ọkunrin ti…

Ile-ẹjọ da Sunday Igboho lare, o ni kawọn DSS san biliọnu lọna ogun Naira fun un

Jọkẹ Amọri Ile-ẹjọ giga kan to jokoo niluu Ibadan, labẹ idari Adajọ Ladiran Akintọla, ti paṣẹ…

Ẹlẹtan ni Oyetọla, ko gbe igbesẹ alaafia kankan pẹlu wa – Awọn TOP

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Alaga The Osun Progressives (TOP), to wa ninu ẹgbẹ oṣelu APC l’Ọṣun, Rẹfrẹndi…

‘Irẹsi ni mo fi owo to kan mi lasiko ta a pa ọmọ sẹnetọ ra, ṣugbọn awọn kọsitọọmu pada gba a lọwọ mi’

Nigba ti awọn agbofinro fọwọ ṣikun ofin mu awọn afurasi agbebọn meji kan, Bashir Muhammed, ẹni…

Awọn gomina Guusu tun ṣepade: Ijọba ipinlẹ ni yoo maa gbowo-ori VAT

Faith Adebọla, Eko Awọn gomina mẹtadinlogun ti ipinlẹ Guusu orileede wa ti kede pe gbọin-gbọin lawọn…

Fani-Kayọde pada sinu ẹgbẹ APC, lawọn eeyan ba ni alasọkojẹ ni

Jọkẹ Amọri Minisita fun ileeṣẹ ọkọ ofurufu nilẹ wa tẹlẹ, Oloye Fẹmi Fani-Kayọde, ti darapọ mọ…

Lẹyin ti Gbajabiamiala fi awọn ajijagbara ‘Yoruba Nation’ we afẹmiṣofo, o loun o sọ bẹẹ mọ

Faith Adebọla, Eko  Olori ileegbimọ aṣoju-ṣofin ilẹ wa l’Abuja, Ọnarebu Fẹmi Gbajabiamila, ti wọn lo sọ…

Bi Jonathan ba fẹẹ dupo aarẹ ninu ẹgbẹ wa ni 2023, aaye wa fun un -APC 

Ẹgbẹ oṣelu APC ti ni bi aarẹ tẹlẹ ni Naijiria, Ọmọwe Goodluck Ebele Jonathan, ba fẹẹ…

 Ọwọ ẹṣọ Amọtẹkun tẹ awọn Fulani meji to rufin ifẹranjẹko l’Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ẹsọ Amọtẹkun ipinlẹ Ondo ti fi pampẹ ofin gbe awọn Fulani meji ti…