Ibi ti Ọlawale ti n kẹru ni ṣọọbu kan ni Surulere lawọn ọlọpaa ka a mọ

Faith Adebọla, Eko Ọjọ gbogbo ni t’ole, ọjọ kan ni tolohun. Ilẹ ọjọ kan ọhun lo…

Ẹfun abeedi, lẹyin ti baale ile kan gba ipe tan lori foonu lo bẹ sodo Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Titi di asiko ti a n ko iroyin yii jọ ni awọn ọlọpaa…

Ile Tinubu ni London di Mẹka fawọn oloṣelu, Ibikunle Amosun naa ti lọọ ki i

Faith Adebọla Ṣe wọn ni ẹni ta o fẹ nile ẹ n jinna, afi bii ẹni…

O ma ṣe o! Wọn ge ori ọkunrin kan, ni wọn ba ju oku ẹ siwaju ṣọọbu n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọbọ, Tọsidee, ọṣẹ yii, ni wọn ri oku ọkunrin kan ti wọn ti…

 Ọkọ da tii gbigbona soju ara iyawo ẹ, o lo ka atẹjiṣẹ ti ale fi ranṣẹ soun

 Lasiko ti a n kọ iroyin yii, awọn ọlọpaa ṣi n wa Alfred Kigena, ọkunrin ọmọ…

Ọmọ ọdun mọkandinlogun yii ba iyawo oniyawo lo pọ, lọkọ ba gun un pa

Ikun n jẹpa, Ikun n rẹdii, Ikun ko mọ pe ohun to dun a maa pa…

Oju arugbo lọmọ ikoko yii gbe waye

Oṣu meji sẹyin ni ọmọ ikoko ti iya rẹ gbe dani yii waye, ṣugbọn niṣe lo…

Awọn agbebọn yii laya o, ilu abinibi gomina Zamfara ni wọn ti lọọ ji ọmọleewe rẹpẹtẹ gbe lọsan-an gangan

Faith Adebọla Kaka ki ewe agbọn dẹ, koko lo n le si i lọrọ awọn janduku…

Nitori ẹsun jibiti, adajọ sọ akẹkọọ Kwara Poli ati akẹgbẹ ẹ sẹwọn n’llọrin 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ọjọ Iṣẹgun, Tusidee, ọṣẹ yii, nile-ẹjọ giga kan niluu Ilọrin, nipinlẹ Kwara, sọ…

Ko ti i ju oṣu mẹjọ lọ ti mo bẹrẹ iṣẹ jija foonu gba, Emeka ni mo maa n ta a fun n’Ikẹja-Balogun

Faith Adebọla, Eko  Ọlajide Balogun lorukọ ọkunrin ẹni ọdun mẹrindinlogoji to wa ninu fọto yii, ọmọ…

Ijọba o gbọdọ fun ẹnikẹni labẹrẹ ajẹsara Korona ni tipatipa-Ile-ẹjọ lo sọ bẹẹ

Faith Adebọla Ile-ẹjọ giga apapọ kan to fikalẹ siluu Port-Harcourt, nipinlẹ Rivers, ti sọ pe ọrọ…