Lori ọrọ owo-ori lori ọja (VAT), ile-ẹjọ da ijọba Rivers ati FIRS lọwọ kọ

Faith Adebọla Ayọ ati idunnu ijọba ipinlẹ Rivers lori ọrọ owo-ori ọja VAT, atawọn ijọba ipinlẹ…

Gbigba owo-ori lori ọja (VAT) dofin l’Ekoo, Sanwo-Olu ti buwọ lu u

Faith Adebọla Gomina ipinlẹ Eko, Babajide Oluṣọla Sanwo-Olu, ti buwọ lu abadofin lori gbigba owo-ori lori…

Ọdunlade Adekọla ṣepe fawọn to ni o n b’awọn obinrin onitiata sun ko too fun wọn niṣẹ

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ọsẹ to kọja yii niroyin gbode nipa Ọdunlade Adekọla, agba oṣere Yoruba to…

Ọmọleewe fa’gbo yo, lo ba ki baba ẹ mọlẹ, o si lu u pa

Faith Adebọla Akẹkọọ ẹni ogun ọdun kan ti wọn lo ṣẹṣẹ ṣedanwo iwe-mẹwaa tan, Mohammed Yusuf,…

Lasiko tawọn agbẹ n ṣiṣẹ ninu oko lawọn afurasi Fulani ji wọn gbe ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Niṣe lawọn afurasi Fulani darandaran ya bo awọn agbẹ kan ninu oko odo…

Ija de: Fẹmi Adeṣina bu Gumi, o n’imulẹ awọn janduku agbebọn ni

Faith Adebọla Isọrọ nigbesi, isunmu-si nigbete-jo, ọrọ yii lo ṣe rẹgi pẹlu bi isọrọ-sira-ẹni ati oko-ọrọ…

Tanka agbepo gbina ni Kwara, eeyan mẹta lo fara pa 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin O kere tan ero mẹta lo mori bọ lọwọ iku ojiji, lasiko ti…

Nitori ọwọngogo ounjẹ, Akeredolu fofin de gbogbo ẹgbẹ oniṣowo nipinlẹ Ondo

Oluṣẹyẹ Iyiade,  Akurẹ Latari bi ọwọngogo ounjẹ ṣe n gbilẹ si i kaakiri ipinlẹ Ondo, Gomina…

 Ẹsọ Amọtẹkun ti ri mẹsan-an gba pada ninu awọn arinrin-ajo ti wọn ji gbe l’Akoko  

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Mẹsan-an ninu awọn arinrin-ajo mejila tawọn agbebọn kan ji gbe lagbegbe Ifira Akoko…

Iwadii bẹrẹ lori awọn mẹta ti wọn yin Stephen lọrun pa, ti wọn tun ji mọto ẹ lọ l’Ekoo

Faith Adebọla, Eko Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n daro iku gigbona tawọn afurasi adigunjale…

Eedi ree o, nitori ounjẹ, iyawo bẹ ọkọ rẹ lori

Titi dasiko yii lawọn eeyan ṣi n kọ haa lori iku ojiji to pa baba kan,…