Igbimọ oluwadii ni Abba Kyari ki i ṣe onijibiti o

Faith Adebọla  Igbimọ tijọba gbe kalẹ lati ṣewadii ẹsun iwa jibiti ati lilẹdi apo pọ pẹlu…

Awọn Hausa naa ni yoo maa ṣejọba lọ ni Naijiria-Oluwoo

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Ogun gidi ni Oluwoo ti ilẹ Iwo, Ọba Abdulrọsheed Adewale Akanbi, gbe ti…

O ma ṣe o, ayẹyẹ ọjọọbi Sunny Ade ku ọla, iyawo rẹ ku lojiji

Faith Adebọla Bi ayẹyẹ ọjọọbi ọdun karundinlọgọrin ti ilu-mọ-ọn-ka agba ọjẹ onkọrin juju nni, Ọmọọba Sunday…

Igbeyawo ku ọsẹ kan, awọn agbebọn ji tọkọ-tiyawo gbe l’Ekiti

Taofeek Surdiq, Ado-Ekiti Lẹyin ọsẹ meji ti awọn ajinigbe gbe ọmọ ati iya kan gbe ni…

Kulikuli ni Rianat fẹẹ lọ ra ti wọn fi pa a, ẹgbẹrun lọna ogun naira lawọn afiniṣowo ra apa ẹ l’Ọffa

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ileesẹ ọlọpaa, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu awọn afurasi afini ṣowo meji,…

Awọn ọmọ ẹgbẹ PDP binu si Makinde n’Ibadan, wọn lawọn ko ni i dibo fun un ni 2023

Adefunkẹ Adebiyi Iyalẹnu lo jẹ fọpọ eeyan niluu Ibadan, lọjọ Aje, Mọnde, ọsẹ yii, nigba ti…

Fifi maaluu jẹko ni gbangba deewọ l’Ekoo, Sanwo-Olu ti buwọ lu ofin rẹ

Faith Adebọla, Eko Ẹnikẹni ti wọn ba mu lori fifi maaluu jẹko ni gbogbo origun mẹrin…

Abẹẹ ri Ọlaoluwa, o si ba ọmọ ẹ lo pọ titi to fi fun un loyun, o niṣẹ Eṣu ni 

Adefunkẹ Adebiyi, Abẹ́òkúta Panpẹ ofin ti mu ọkunrin yii, Ọlaoluwa Jimọh, ẹni ọdun marundinlaaadọta (45) to…

Nitori to n ta ẹran to ti bajẹ fawọn araalu, sifu difensi mu alapata kan ni Kwara 

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ajọ ẹsọ alaabo ṣifu difẹnsi, ẹka ti ipinlẹ Kwara, ti mu ẹlẹran maaluu…

Ti ipo Aarẹ ba tun bọ si Oke-Ọya, ẹni ti ko ba nifẹẹ si i le kẹru ẹ kuro lorileede yii – Awọn agbaagba ilẹ Hausa

Faith Adebọla Latari ipade tawọn gomina iha Guusu ilẹ wa ṣe l’Ọjọbọ ọsẹ to kọja, nibi…

Awọn araalu binu dana sun afurasi ajinigbe mẹfa tọwọ tẹ

Faith Adebọla Agbako gidi lo ba awọn afurasi ajinigbe mẹfa kan tọwọ tẹ lagbegbe Tangaza, nijọba…