Nitori ki wọn le fopin si ogun Gaza, ọkunrin ologun yii dana sunra ẹ

Monisọla Saka Kayeefi ni ọrọ Aaron Bushnell, ọkunrin ọmọ ogun oju ofurufu ilẹ Amẹrika kan jẹ…

Ṣẹyin naa ti gbọ ohun to ṣẹlẹ si Lalaa onitata

Monisọla Saka Ẹsẹ o gbero laduugbo Salami Shittu Street, l’Opopona Pedro, Bariga, nipinlẹ Eko, nibi ti…

Inu mọto tawọn ọmọ iya mẹta ti n ṣere looru mu wọn pa si n’llọrin

  Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Ere lawọn ọmọ iya mẹta kan tọjọ ori wọn wa laarin ọmọọdun…

Makinde ti ileeṣẹ awọn Chinese pa n’Ibadan, o tun sọ awọn oṣiṣẹ wọn satimọle

Ọlawale Ajao, Ibadan Nnkan ko ṣẹnuure fawọn ara orile-ede China kan ti wọn da ileeṣẹ nla…

Mo kan sanwo idana danu lori iyawo mi ni, mi o ṣe mọ o-Kazeem

Adewale Adeoye Iwaju Onidaajọ, Abilekọ S.M Akintayọ, tile-ẹjọ kọkọ-kọkọ kan to wa lagbegbe Mapo, niluu Ibadan, ipinlẹ Ọyọ, ni awọn tọkọ-taya meji kan, Ọgbẹni Kazeem ati Abilekọ Sherifat, gbẹjọ ara wọn lọ lopin ọsẹ to kọja…

Lẹyin tawọn agbebọn gbowo itusilẹ tan, wọn tun pa ẹni ti wọn ji gbe l’Abuja

Adewale Adeoye Afi kawọn alaṣẹ ijọba orileede yii tete gbe igbesẹ gidi lori ọrọ awọn agbebọn ti wọn ti fẹẹ sọra…

O ṣẹlẹ! Portable ko Laide Bakare sita bii ọmọ ọjọ mẹjọ

Monisọla Saka Gbajugbaja arẹwa oṣerebinrin ilẹ wa nni, Laide Bakare, lo ti ṣe bẹẹ daran lọwọ…

Eeyan meje padanu ẹmi wọn nibi ti wọn ti n gba irẹsi tawọn kọsitọọmu n pin

Monisọla Saka Latari bi ilu ṣe le koko, ti ebi si n pa araalu, eeyan meje…

Wọn ri ọmọ ọdun meji he l’Ọṣun

Florence Babaṣọla, Oṣogbo Ọkunrin kan to n bọ lati iṣọ-oru laago marun-un kọja iṣẹju mẹwaa aarọ…

Awọn fijilante pa ajinigbe kan, wọn ri meji mu, wọn tun gba obinrin meji ti wọn ji ni Kwara silẹ

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Nnkan o ṣẹnuure fun awọn ajinigbe kan ti wọn ji eeyan mẹta gbe…

Ọwọ ọlọpaa tẹ awọn ajinigbe meji, wọn doola ọmọleewe ti wọn ji gbe

Monisọla Saka Ọwọ ileeṣẹ ọlọpaa ipinlẹ Eko ti tẹ awọn ole ajọmọgbe meji kan, Bọlajoko Haruna…