Baba Adeboye ti sọrọ: Eyi lọna abayọ si iṣoro Naijiria

Pasitọ agba ati olori ijọ Onirapada patapata, The Redeemed Christian Church of God (RCCG), Pasitọ Enoch…

Eyi ni bi Cote D’Ivore ṣe gba ife-ẹyẹ bọọlu ilẹ Afrika!

Faith Adebọla Lẹyin aadọrun-un iṣẹju ti ẹgbẹ agbabọọlu Super Eagles ti ilẹ Naijiria ti wa a…

APC sọkọ ọrọ si Atiku ati Peter Obi

Adewale Adeoye Ni bayii, ẹgbẹ kan to n ṣatilẹyin ati ipolongo fun ẹgbẹ oṣelu APC ‘The Confederation Of All Progressive Congress Support Group’ ti sọkọ ọrọ sawọn oloṣelu…

Ọmọ Naijiria yii ti ha o, oogun oloro lo gbe lọ si India

Adewale Adeoye Awọn alaṣẹ ijọba orileede India ti fọwọ ofin mu ọmọ orileede wa kan torukọ rẹ n je David Okpara, ati ọmọ orileede Ghana…

Nitori asọtẹlẹ to sọ, ẹgbẹ APGA fẹẹ gbena woju Primate Ayọdele

Monisọla Saka Ẹgbẹ oṣelu The All Progressives Grand Alliance (APGA), ti sọko ọrọ si gbajumọ wolii…

Mọto ayọkẹlẹ fori sọ tirela ati kẹkẹ Marwa, eeyan meji ku, mẹta fara pa gidigidi

Mọto ayọkẹlẹ fori sọ tirela ati kẹkẹ Marwa, eeyan meji ku, mẹta fara pa gidigidi Adewale Adeoye Titi di asiko…

Aṣiri tu! Eyi lohun to fa ijamba baaluu to pa ọga agba Access bank, iyawo atọmọ rẹ

Faith Adebọla Awọn alaṣẹ ijọba orileede Amẹrika ti ṣalaye ohun to ṣokunfa ijamba ọkọ ofurufu hẹlikọpita…

Eyi ni aṣiri bi ọga agba banki Access, iyawo ati ọmọ rẹ ṣe ku sinu ijamba ọkọ ofurufu l’Amẹrika

Faith Adebọla Ọga agba ọkan lara awọn banki to loookọ nilẹ wa, Access Holdings Limited, Ọgbẹni…

 Awọn ajinigbe ṣ’ọṣẹ l’Akoko, wọn pa dẹrẹba, wọn tun ko ero rẹ wọgbo lọ

Oluṣẹyẹ Iyiade, Akurẹ Ọrọ awọn ajinigbe to n ṣoro bii agbọn nipinlẹ Ondo ti waa di…

Akẹkọọ Fasiti KWASU yii gbẹmi ara rẹ, eyi lohun to fa a

Ibrahim Alagunmu, Ilọrin Rashidat Shittu, orekelẹwa akẹkọọ ileewe Fasiti tipinlẹ Kwara (KWASU), to wa ni Màlété,…

Ta lo maa gba ife ẹyẹ AFCON laarin Nigeria ati Cote D’Ivore

Faith Adebọla O ti ṣẹlẹ! Gbẹgẹdẹ fẹẹ gbina! Bi ohun kan ba wa to maa n…