Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Adabọnyin Ẹkun, Ọba Adetokunbọ Gbadegẹṣin Tẹjuoṣo, Olu Orile Kemta, l’Abẹokuta, to sọrọ soke…
Category: Ìròyìn
Eyi lawọn ohun to n fa wahala lawọn ile-ẹkọ yunifasiti wa
Ni orilẹ-ede Naijiria tiwa loni-in yii, o fẹrẹ ma si ọdun kan ti awọn olukọ yunifasiti…
O ma ṣe o! Akẹkọọ Fasiti LAUTECH ja sinu sọkawee, lo ba ku patapata
Ọlawale Ajao, Ibadan Waiwai ni inu ọgba Ladoke Akintọla University of Technology (LAUTECH), to wa niluu…
Wọn tun ji Abraham gbe l’Ayetẹ
Ọlawale Ajao, Ibadan Ọrọ awọn arinrianjo ti wọn ji gbe lọna Eruwa la ṣi n sọ…
Ọkada lawọn eleyii lọọ ji gbe tọwọ fi tẹ wọn ni Kwara
Stephen Ajagbe, Ilorin Afurasi mẹta; Abdullahi Yaro, Abdulganiu Muhammed ati Baki Adamu, ni wọn ti ko…
Awọn janduku dana sun ile gomina ipinlẹ Imo, wọn tun pa ẹṣọ meji
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Laaarọ ọjọ Abamẹta, Satide, ọjọ kẹrinlelogun, oṣu kẹrin yii, ni awọn janduku kan…
Ẹ kilọ fun Fayẹmi ko ma ta ilẹ wa fawọn Fulani o-PDP Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Ẹgbẹ People’s Democratic Party (PDP) ipinlẹ Ekiti ti fẹsun kan Gomina Kayọde Fayẹmi…
Ọlọpaa ti ri Alaga ti wọn ji gbe l’Oke-Onigbin, nipinlẹ Kwara, gba pada
Stephen Ajagbe, Ilorin Ọga ọlọpaa ni Kwara, Mohammed Lawal Bagega, ti kede pe awọn doola oniṣowo…
Awọn agbebọn ji alakooso kansu l’Ekiti
Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Awọn agbebọn ti ji alakooso fun eto ọgbin nijọba ibilẹ Iwọ-Oorun Ekiti, Ebenezer…
Ti mo ba tun aye wa, Yinka ni ma a fẹ – Joe Odumakin
Florence Babaṣọla, Oṣogbo Iyawo Oloogbe Yinka Odumakin, Joe, ti sọ pe to ba ṣee ṣe fun…
Ara Kẹmi Afọlabi, oṣere tiata, ko ya o
Adefunkẹ Adebiyi, Abẹokuta Kẹmi Afọlabi Adeṣipẹ, ọkan lara awọn oṣerebinrin nilẹ yii, ti jẹ ko di…