Ẹgbẹ okunkun lawọn eleyii n ṣe n’Ikorodu, kọmiṣanna ọlọpaa lo mu wọn

Faith Adebọla, Eko   Ọwọ ọlọpa ti tẹ marun-un lara awọn gende to n ṣe ẹgbẹ…

Moshood ati Lekan fi aake gba ọkada l’Ekoo, nile-ejọ ba ni wọn lọọ yẹgi fun wọn

Faith Adebọla, Eko Ibi tawọn afurasi adigunjale meji kan, Moshood Ogunṣọla ati Ọlalekan, foju si, ọna…

Akẹkọọ-jade Fasiti KWASU to lu jibiti yoo ṣẹwọn oṣu mẹfa

Stephen Ajagbe, Ilorin Adajọ Sikiru Oyinloye tile-ẹjọ giga ipinlẹ Kwara, ti ju akẹkọọ-jade ileewe Fasiti KWASU, …

Lẹyin ọdun mẹta ti wọn lo nipo, Oyetọla ni ki gbogbo awọn alaga kansu kuro lọfiisi

Florence Babaṣọla Gomina ipinlẹ Ọṣun, Alhaji Gboyega Oyetọla, ti sọ pe ki gbogbo awọn alaga ijọba…

‘Bi Buhari ṣe ni ki ọga ọlọpaa patapata maa baṣẹ lọ tapa sofin’

Faith Adebọla Awọn amofin agba meji kan nilẹ wa, Ẹbun-Olu Adegoruwa ati Mike Ozekhome, ti kede…

Laarin ọsẹ mẹta, obinrin mẹrin bimọ fun kafinta yii, o logoji ọmọ loun fẹẹ bi

Nura Walwala lorukọ ọkunrin to duro laarin awọn obinrin mẹrin yii, ẹni ọdun mẹrindinlogoji ni, oun…

Ọmọbinrin yii pokunso, nitori ti wọn lo ji pata

Bi ẹ ti n wo ọmọbinrin daadaa yii, ko si laye mọ. Ọgbọnjọ, oṣu kin-in-ni, ọdun 2021…

Ọọni loun ko binu si Sunday Igboho mọ, oun ko si ni i sọrọ lori ohun to ṣe

Ki awueywye to gbode kan le dohun igbagbe patapata lori bi Oloye Sunday Igboho ṣe fẹnu…

Ijọba ti ko awọn ti Fulani ṣa ladaa n’Ibarapa lọ sileewosan UCH, n’Ibadan

Faith Adebọla Ọjọ kẹrin lẹyin ti Gomina ipinlẹ Ọyọ, Ṣeyi Makinde, ṣeleri lati mojuto awọn ti…

Arun Korona tun pa eeyan marun-un l’Ekoo

Faith Adebọla  Arun Koronafairọọsi to ti di ẹrujẹjẹ kari aye bayii ti tun da ẹmi eeyan…

Awọn eeyan binu si ọmọ Wasiu Ayinde to n bu Sunday Igboho

Aderohunmu Kazeem Pelu ibinu lawọn eeyan fi n ṣepe le ọmọ Alaaji Wasiu Ayinde, Arabinrin Damilọla…