O ma ṣe o, ọmọ ileegbimọ aṣofin Ekiti ku lojiji

Oluyinka Soyemi, Ado-Ekiti Aṣofin to n ṣoju ẹkun Ila-Oorun Ekiti nile igbimọ aṣofin ipinlẹ naa, Oluwajuwa…

Wọn ni wọn fun Sadiku Dodo, abẹṣẹ-ku-bii-ojo ọmọ Yoruba to ku ni majele jẹ ni

Ọlawale Ajao, Ibadan Abẹṣẹ-ku-bii-ojo ọmọ Ijẹbu-Igbo to n ṣoju orilẹ-ede yii, Akeem Sadiku, ẹni tọ́pọ̀ eeyan…

Gomina Kano, Abdullahi Ganduje, pe fun ofin ti yoo de awọn Fulani lati maa da ẹran kaakiri

Gbogbo awọn ti wọn gbọ ọrọ ti Gomina ipinlẹ Kano, Abdullahi Ganduje, sọ pe ki ijọba…

Fulani deegun ẹja si wọn lọrun l’Ayetẹ, o ni pipa loun yoo pa Yoruba to ba gba ọna ile oun kọja

Ọlawale Ajao, Ibadan Wahala mi-in tun n rúgbó bọ̀ niluu Ayétẹ̀, nijọba ibilẹ Ariwa Ìbàràpá bayii,…

Nibi tawọn ajagungbalẹ ti n da awọn eeyan laamu labule kan l’Ewekoro lọwọ ọlọpaa ti ba mẹsan-an ninu wọn

Adefunkẹ Adebiyi,Abẹokuta Biba ni wọn ni awọn ajagungbalẹ ya bo abule Agbogun, nijọba ibilẹ Ewekoro, nipinlẹ…

Ẹ gba bi mo ṣe sọ, wahala awọn Fulani ilu Igangan yoo dopin lọsẹ yii – Alaga ijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa

Faith Adebọla Alaga ijọba ibilẹ Ariwa Ibarapa, Ọnarebu Iliasu Ọlọlade Shittu, ti fọwọ sọya pe laarin…

O ṣẹlẹ, awọn Fulani rẹpẹtẹ ti tun ya wọ Igangan, aṣọ bii tawọn Amọtẹkun ni wọn wọ

Faith Adebọla Ko jọ pe iṣoro iwa ọdaran, ijinigbe, ipakupa ati biba ire oko awọn agbẹ…

Awọn obinrin abule Okemiri, niluu Oro, lawọn yoo filu silẹ tawọn Fulani to sa wa lati Igangan ko ba kuro niluu awọn

Awọn obinrin to wa ni abule kan ti wọn n pe ni Okemiri, niluu Oro, nipinlẹ…

Awọn Fulani to sa lọ si Kwara lati Igangan ti tun fẹẹ rija awọn eeyan abule Okemiri to gba wọn lalejo niluu Oro

Stephen Ajagbe, Ilorin Ẹgbẹ kan to jẹ tawọn ọmọ bibi ẹkun Guusu Kwara, iyẹn Kwara South…

Awọn tọọgi kọ lu kọmisanna, wọn tun ṣe awọn mi-in leṣe nibi iforukọsilẹ ẹgbẹ APC n’Iju

Oluṣẹyẹ Iyiade   Ọpọlọpọ eeyan lo fara pa ninu rogbodiyan kan to bẹ silẹ nibi tawọn…

Sunkanmi atawọn ọrẹ ẹ fẹẹ pa Tẹslim, nitori tiyẹn loun ko ba wọn ṣẹgbẹ Ẹyẹ

Ọwọ ọlọpaa ti tẹ awọn janduku ọmọ ẹgbẹ okukun mẹta kan lori pe wọn n fi…